YBTC News YORÙBÁ— Àwọn ikọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn ti ẹka Òǹdó ti dóòlà àwọn obìnrin méjì àti ọkùnrin kan tí àwọn àjinigbé gbé nígbà tí wọn ń bọ̀ láti ìpínlẹ̀ Benue lọ sí Àkúrẹ́ fún ìjọsìn. Orúkọ àwọn tí wọn gbé náà ni Adéwálé Adébísí, ẹni ọdún 53, méjìléláádọ́ta, Arábìnrin Ahan Mary ẹni ọdún mọ́kànlélógún àti arábìnrin […]
