Categories
Ìròyìn

Ki APC Fa Ènìyàn Sílẹ̀ Lati Àríwá Fún Ipò Ààrẹ 2023 Túmọ́ Sí Sáà Kẹta Ni – Ndume

YBTC News YORÙBÁ— Adarí ilé Aṣòfin àgbà ní Abùjá nígbà kan rí, Sen. Ali Ndume, ti ẹgbẹ́ òṣèlú APC, ní ìhà gúsù Borno ti bu ẹnu àtẹ́ lu bí àhesọ ọ̀rọ̀ ṣe ń lọ pé láti ìhà àríwá ni ọmọ oyè ààrẹ yóò ti wá. Ó ní tí ẹgbẹ́ òṣèlú APC bá leè fi irú […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Ọmọ OOU Méjì Tí Wọ́n Gbé Ti Rí Ìtúsílẹ̀

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwé gíga OOU méjì tí àwọn àjinigbé lọọ fi ipá gbe sálọ ní wọ́n ti rí Ìtúsílẹ̀. Ilé ìwé OOU èyí tí ó wà ní Ayétòrò. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà, Dàpọ̀ Abiọdun ti sọ fún aráyé lórí ìkànnì ayárabíàsá, ayélujára rẹ̀ wípé àwọn ọmọ obìnrin náà, Precious Adeyemo àti […]

Categories
Ìròyìn

Wàkílí Di Èrò Àtìmọ́lé Lórí Ẹ̀sùn Apànìyàn Àti Ajínigbé

YBTC News YORÙBÁ— Adájọ́ àgbà ní ilé ìdájọ́ gíga Májísíréètì Iyaganku tí ó kalẹ̀ sí ìlú Ìbàdàn, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti pàṣẹ pé kí wọn lọ ju afurasí ògbóǹtarìgì fulani kan, Wàkílí sí àtìmọ́lé. Wọ́n dìjọ fi ẹ̀sùn kan Wàkílí àti ọmọ rẹ̀, Abu, ẹni ọdún máárùndínláádọ́ta, pẹ̀lú Samaila, ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún àti Aliyu Mamu, […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Ti Ṣe Ìkọlù Sí Àyè Ìwakùsà Ní Ìbàdàn, Wọ́n Gbé Èèyàn Meji

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn agbebọn kan tí a kò mọ̀ ti ṣe ìkọlùsí àyè kan tí wọn ti ń wa kusa ní ìbàdàn, olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ní agbègbè abúlé Dali, ní pópónà márosẹ̀ Ibadan sí Ìjẹ̀bú Òde. Ìròyìn tí ó tẹ̀wá kétí jẹ́ kí á mọ̀ pé àwọn agbébọn náà yawọ àyè ìwakùsà ọ̀hún […]

Categories
Ìròyìn

Fasoranti Sọ̀kalẹ̀ lórí Àlééfà, Ẹ Wo Adari Titun Afẹ́nifẹ́re

YBTC News YORÙBÁ— Olóyè Ayọ̀ Adébánjọ ni ẹni tí yóò máa wà gẹ́gẹ́ bíi olùdarí titun tí ẹgbẹ́ àkójọpọ̀ ọmọ Yorùbá àtàtà, Afẹ́nifẹ́re ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn, ní tilé toko. Yíyàn sípò rẹ̀ ti fa fífi ipò sílẹ̀ olùdarí ẹgbẹ́ náà tẹ́lẹ̀, Baba Reuben Fasoranti, ẹni tí ó sọ̀kalẹ̀ lórí àlééfà ní òní ọjọ́ ajé látàrí pé […]

Categories
Ìròyìn

Kòsí Àyè Fún Darandaran Ní Òǹdó – Akérédolú

YBTC News YORÙBÁ— Gómìnà ìpínlẹ̀ Òǹdó, ọ̀gbẹ́ni Rótìmí Akérédolú ti sọ ọ́ kedere wípé òun kò níí fún àwọn darandaran ní ilẹ̀ kankan ní ìpínlẹ̀ Òǹdó Ó ní dípò kí òun fún wọn nílẹ̀, òhun á kúkú gùn lórí ìlànà ìjọba àpapọ̀ láti ríi wípé ìjà àti ìpara ẹni láàrín àwọn àgbẹ̀ àti fúlàní darandaran […]

Categories
Ìròyìn

Oyetola Ti Tún Alákijà Yàn Gẹ́gẹ́ Bí Ọ̀gá Àgbà Uniosun

YBTC News YORÙBÁ—  Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Gboyega Oyetola ti tún yan olówó, ọlẹ jaburata, Fọ́lọ́runsọ́ Alákijà, fún ọdún máárùn-ùn gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà,(chancellor) ilé ẹ̀kọ́ gíga UNIOSUN. Agbẹnusọ fún ilé ìwé gíga ọ̀hún, ọ̀gbẹ́ni Adesoji Ademola sàlàyé ní àná ọjọ́ ajé wípé títún yàn sípò Alákijà wáyé látàrí ipa ribiribi tí ó tií kó àti […]

Categories
Ìròyìn

Ìjọba Òǹdó Ti Fún Àwọn Olùkọ́ Tí Wọn Ṣẹ̀ṣẹ̀ Gbà Ní Lẹ́tà Ayọ

YBTC News YORÙBÁ— Ìròyìn ti fi tówa létí pé àwọn olùkọ́ni titun tí ìjọba ìpínlẹ̀ Òǹdò ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà ábẹ́ ìṣàkóso àjọ tó ń ṣe àmójútó ilé-ìwé alákọ́bẹ̀rẹ̀, SUBEB ti bẹ̀rẹ̀ sí níí gba lẹ́tà ìgbaniṣíṣẹ́. Akọ̀wé àgbà fún gómìnà ìpínlẹ̀ náà, Ọ̀gbẹ́ni Rotimi Akérédolú, ìyẹn Olabode Richard Olatunde fi ìdí ọ̀rọ̀ náà múlẹ̀ pé lóòótọ́ […]

Categories
Ìròyìn

Ẹ̀mí Sòfò Ní Akwa Ibom! Bí Ọkọ Epo Ńlá Se Kọlu Kẹ̀kẹ́

YBTC News YORÙBÁ— Ènìyàn mẹ́fà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ló gbẹ́mí mì lójú ẹsẹ̀, tí wọn sì Jóná ráúráú pẹ̀lú bí ọkọ̀ ńlá tó gbé epo bẹntiro se kọlù ki ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́ta kan ní Akwa Ibom. Èyí ṣẹlẹ̀ ní abúlé Ntak Inyang, tí kò ju kìlómítà díẹ̀ sí Uyo. A gbọ́ pé lójú ẹṣẹ̀ tí ọkọ̀ epo nlá […]

Categories
Ìròyìn

Ọmọ Akẹ́kọ̀ọ́ OOU Méjì Ni Àwọn Agbébọn Ti Gbé

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin méjì ilé ìwé ńlá Yunifásitì Olabisi Onabanjo(OOU) ní ìpínlẹ̀ Ògùn ni àwọn afurasí agbébọn ti gbé lọ. Àwọn ọmọ méjì ọ̀hún náà ni Adeyemo Precious àti Oyefule Abiola. Ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ọ̀hún ń ṣe iṣẹ́ ìmọ̀ Ojúgbó àti ìṣàkóso àwọn ẹ̀dá abàmì inú igbó, èkejì sì ń […]