Categories
Ìròyìn

ASUP Kìlọ̀ Fún Buhari Wípé Àwọn Ó Gùn Lé Ìyanṣẹ́ Lódì

YBTC News YORÙBÁ—Àjọ tí ó ń rí sí ilé ìwé gígaonímọ̀ ẹ̀rọ̀ polí, ASUP tí dún mọ̀hurumọ̀huru mọ́ ààrẹ Muhammadu Buhari wípé àwọn yóò gùn lé ìyanṣẹ́ lódì ní ọjọ́ kẹfaà, oṣù tó ń bọ̀. Òní ọjọ́ ẹtì ni ibi àpérò àwọn olórí wọn ní ìpínlẹ̀ Katshina. Ààrẹ àjọ náà, Anderson Ezeigbe ṣàlàyé wípé ìgbésẹ […]

Categories
Ìròyìn

Ìjà Ẹ̀sìn: Ìjọba Kwara Ti Rán Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Sí Àwọn Ilé Ìwé Tí Wọ́n Tìpa

YBTC News YORÙBÁ—Inú fu- àyà fu àti ìbẹ̀rù ti bo ìlú Ìlọrin, olú ìlú Kwara kan láti ìgbà tí ìjọba ìpínlẹ̀ náà ti pàṣẹ pé kí wọn ti àwọn ilé ìwé ìhìnrere ẹlẹ́sìn kristẹ̀nì pa. A ríi gbọ́ wípé àwọn ilé ìwé náà tako ìlo hijab (ìborí mùsùlùmí) láàrin àwọn ọmọ ilé ìwé tó jẹ́ […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

“Mọ̀ nípa Ọgágun Amao tí Buhari ṣẹ̀ṣẹ̀ Yàn”(Chief of Air Staff)

“Mọ̀ nípa Ọgágun Amao tí Buhari ṣẹ̀ṣẹ̀ Yàn”(Chief of Air Staff)-YBTC NEWS YORÙBÁ Air Marshal Isiaka Oladayo Amao, wọ́n bí i ní ojó kẹrinla Oṣù Kẹsàn-án 1965, bíbí àti dàgbà ní Ìpínlè Enugu Gúúsù ìlà oòrùn Nigeria. Lẹ́yìn náà ó lọ sí ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun pẹ̀lú àwọn òbí rẹ̀ kì wón tún tó lọ sí ìpínlẹ̀ […]

Categories
Ìròyìn

Ààrẹ Ilé Aṣòfin Àgbà Ilẹ̀ Yìí Rọ Ìjọba Àpapọ̀ Láti Pèsè Ètò Irànwọ́ Fún Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Bí Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ṣe ń Jókòó Sílé Báyìí

YBTC News Yorùbá-Ààrẹ ilé Aṣòfin Àgbà ilẹ̀ yìí, ìyẹn Aṣòfin Ahmad Lawan ti ké sí ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ yìí wípé kí ó yára pèsè ètò irànwọ́ fún àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè yìí tí ó jẹ́ wípé jíjòkò sílé yóò ṣe àkóbá ńláńlá fún iṣẹ́ òòjọ́ wọn. Lawan nínú ọ̀rọ̀ tí ó fi léde láti ẹnu […]

Categories
Ìròyìn

Ilé Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó Pe Àwọn Aṣòfin Tí Wọ́n Jáwe Gbéléẹ Fún Padà

YBTC News Yorùbá-Ilé Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó ti pe àwọn Aṣòfin tí ó jáwe gbélé ẹ lé lọ́wọ́ ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹta ọdún yìí padà sí ilé Aṣòfin náà. Agbẹnusọ ilé Aṣòfin náà ní ọjọ́ ọjọ́bọ kéde ìpenipadà náà ní ọjọ́ ọjọ́bọ nígbà tí Ìjíròrò ń lọ lọ́wọ́ Àwọn Aṣòfin mẹ́ta tí ọ̀rọ̀ náà kán […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ní Orílẹ̀ Èdè Spain, Wọ́n Sọ Pápá Ìṣeré Real Madrid Di Ibi Ìkó Èròjà Ìtọ́jú Àláàrẹ̀

YBTC News Yorùbá-Ikọ̀ Real Madrid ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé pápá ìṣeré Ikọ̀ ọ̀ún ni wọn ó ma lò fún ibi ìkó èròjà ìtọ́jú aláàrẹ̀ sí báyìí láti fún orílẹ̀ èdè náà ní àǹfààní láti kọjú àìsàn apanirun kòkòrò Coronavirus. Pápá ìṣeré tí ó gba kọjá ènìyàn lé lọ́nà ẹgbẹ̀rún ọgọ́rin ni wọn ó máa […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Mẹ́fà Kan Tí Wọ́n Lu Gbẹ́dẹ Àrùn Coronavirus Ni Àyẹ̀wọ̀ Fi Hàn Báyìí Wípé Wọn Kò Ní Àrùn Náà Mọ́

YBTC News Yorùbá-Olùbáni Dámọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ ìlera fún gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó, ìyẹn Dókítà Tunde Ajayi ti sọ fún àwọn oníròyìn wípé àwọn mẹ́fà lára àwọn tí ó lu gbẹ́dẹ àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus ní ara wọn ti yá báyìí. Ajayi lórí ẹ̀rọ alátagbà rẹ̀, ìyẹn Twitter ní ọjọ́ ọjọ́bọ sọ pé àwọn mẹ́fà nínú àwọn […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ìdí Rèé Tí Mofi Fi Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Arsenal Sílẹ̀ – Ajayi Lahùn

YBTC News Yorùbá-Agbábọ́ọ̀lù nípò ẹ̀hìn fún ikọ̀ West Brom ní orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìyẹn Semi Ajayi ti ṣàlàyé fún àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ ìdí tí òun fi fi Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lú Arsenal sílẹ̀ lọ sí Ikọ̀ míràn lẹ́yìn sáà igbábọ́ọ́lù méjì péré. Ajayi sọ pé òun ń wá Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú tí ó jẹ́ wípé òun ma […]

Categories
Ìròyìn

Mo Jábalé Ọmọ Ọdún Mẹ́rin Nítorí Wípé Ọ̀rẹ́ Ni Àwa Méjèèjì

YBTC News Yorùbá-Ọmọ ogún ọdún kan rèé ni ó ti kó sí akóló àwọn Ọlọ́pàá báyìí látàrí ẹ̀sùn ìjábalé ọmọ ọdún mẹ́rin kan, tí ó ní ọ̀rẹ́ òun ni. Arákùnrin náà tí ó pè ní Ọ̀gbẹ́ni Isaac Boniface ni ó ti jábalé ọmọ obìnrin ọmọ ọdún mẹ́rin ní àdúgbò Danwoh ní gúúsù Jos ní ìpínlẹ̀ […]

Categories
Ìròyìn

Ìdí Rèé Tí A Kòle Ta Jálá Epo Kan Ní Márùn-únlèélọ́gọ́fà Owó Náírà – Àwọn Ọlọ́jà Epo Pẹtiró

YBTC News Yorùbá-Àwọn ọlọ́jà ilé epo pẹtiró nílẹ̀ yìí kò í tíì bẹ̀rẹ̀ sí ní ma ta jálá epo pẹtiró ní Márùn-únlèélọ́gọ́fà owó náírà tí Ìjọba àpapọ̀ pàṣẹ wípé tí wọ́n máà tá epo náà, ṣùgbọ́n àwọn ilé iṣẹ́ elépo tí Ìjọba nìkan ni ó ń tà á ní iye tí Ìjọba fọwọ́sí. Àwọn ilé […]