Categories
Ìròyìn

WAEC Ti Kéde Ọjọ́ Tí Ìdánwò Yóò Bẹ̀rẹ̀. Ẹ Wo Ọjọ́ Náà

YBTC News YORÙBÁ— Àjọ tí ó ń rísí ìdánwò fún àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ìhà ìwọ̀-oòrùn adúláwọ̀ WAEC, ti kéde pé ìdánwò yóò bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹjọ títí di ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹẹ̀sán, 2021. Ẹ rántí wípé adarí àjọ náà, Patrick Areghan tí sọ tẹ́lẹ̀ wípé ó ṣe é ṣe kí ìdánwò WAEC tí […]

Categories
Ìròyìn

Akérédolú Pàṣẹ Kí Wọn Dá Owó WAEC Padà Fún Àwọn Òbí

YBTC News YORÙBÁ— Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó, Ọ̀gbẹ́ni Rótìmí Akérédolú ti pàṣẹ fún àwọn ọ̀gá ilé ìwé jákèjàdò ìpínlẹ̀ náà pé kí wọn dá owó ìdánwò WAEC tí àwọn òbí ti san padà fún wọn. Akọ̀wé àgbà fun ẹka ètò ẹ̀kọ́ ìpínlẹ̀ náà, Lolá Amuda ló fi ọ̀rọ̀ ọ̀ún tó àwọn ọ̀gá ilé ìwé ìjọba jájèjádò […]