Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Àmọ̀tẹ́kùn Yóò Kùnà, Àyàfi… Tinubu Padà Sọ̀rọ̀ Lórí Àmọ̀tẹ́kùn, Kòní Óda Tàbí Kòda

YBTC Yorùbá- Ògbóntàrigì àgbàlagbà ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC) Asiwaju Bola Tinubu ti sọ wípé Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò ìyẹn Àmọ̀tẹ́kùn tí àwọn gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀. Tinubu ní èròǹgbà àwọn Gómìnà náà da bẹ́ẹ̀ sì ni ìdásílẹ̀ Àmọ̀tẹ́kùn ṣe kókó ṣùgbọ́n ó ṣeéṣe kí èròǹgbà tí wọ́n ní fún […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Àmọ̀tẹ́kùn Yóò Kùnà, Àyàfi… Tinubu Padà Sọ̀rọ̀ Lórí Àmọ̀tẹ́kùn, Kòní Óda Tàbí Kòda

Ògbóntàrigì àgbàlagbà ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC) Asiwaju Bola Tinubu ti sọ wípé Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò ìyẹn Àmọ̀tẹ́kùn tí àwọn gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀. Tinubu ní èròǹgbà àwọn Gómìnà náà da bẹ́ẹ̀ sì ni ìdásílẹ̀ Àmọ̀tẹ́kùn ṣe kókó ṣùgbọ́n ó ṣeéṣe kí èròǹgbà tí wọ́n ní fún Àmọ̀tẹ́kùn forí […]

Categories
Ìròyìn

Adebanjo, Okunronmu àti Àwọn Yòókù Dìgbòlu Tinubu Bí ó Ṣe Dákẹ́ Lórí Ọ̀rọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn

YBTC Asíwájú àgbà nínú ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re, ìyẹn Pa Ayo Adebanjo àti Aṣòfin Femi Okunronmu ní ọjọ́ àbàmẹ́ta sọ̀rọ̀ kùgbákùgbé sí Asíwájú àgbà nínú ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), ìyẹn Asiwaju Bola Tinubu bí ó ṣe kùnà láti sọ̀rọ̀ lórí Àmọ̀tẹ́kùn. Ṣùgbọ́n agbẹnusọ fún Asiwaju Tinubu sọ wípé àsìkò kò ì tìí tó ló fà […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Àwọn Ẹgbẹ́ Kan Ti Fún Tinubu Ní Wákàtí Méjìlélógún Láti Fi Ìpínnu Rẹ̀ Hàn Lórí Àmọ̀tẹ́kùn

YBTC Yorùbá-Àwọn ẹgbẹ́ kan ni Ìwọ̀ Oòrùn Gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ti amọ̀sí Save Lagos Group ti fún Alága Abẹ́lé nínú ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), Asiwaju Bola Tinubu ni gbèdéke wákàtí méjìlélógún láti fi fi èrò rẹ̀ hàn sí àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí Àmọ̀tẹ́kùn. Tinubu tí àwọn ènìyàn rí bi asíwájú ní Ìwọ̀ Oòrùn […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Irọ́ Funfun Búláú Ni, Èmi Ò Bá Tinubu, Atiku Ṣe Ìpàdé Kankan Lórí Dídá Ẹgbẹ́ Òṣèlú Míì Sílẹ̀ – Maku

YBTC Yorùbá—Ọ̀gbẹ́ni Labaran Maku, tí ó jẹ́ Akọ̀wé Gbogbogbò ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Grand Alliance (APGA) ti ṣe àpèjúwe ìròyìn tó ní òun ṣe ìpàdé pẹ̀lú Asiwaju Bola Tinubu ti All Progressive Congress (APC) àti Atiku Abubakar ti PDP gẹ́gẹ́ bi ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀. Maku ni òun kò ní ìpàdé pẹ̀lú ẹnìkankan láti lè dá ẹgbẹ́ […]