Categories
Ìròyìn

Ẹ Wo Ohun Tí Makinde Ṣèlérí Wípé Òhun Á Fún Àwọn Tí Iná Jó Dúkìá Wọn Ní Ìbàdàn

YBTC News YORÙBÁ— Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Onímọ̀ ẹ̀rọ Ṣèyí Mákindé ti ṣe ìpàdé pọ̀ pẹ̀lú àwọn aṣojú àti ọ̀tọ̀ǹkùlú àwọn oníṣòwò ẹ̀yà ara ọkọ̀ tí iná sé ìjànbá fún ni Agidi Gate nílú Ìbàdàn. Ìpàdé náà ni láti dín òfò àti ǹkan tí ó nù wọ́n kù àti láti fún àwọn tó fara gbá nínú […]

Categories
Ìròyìn

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Oyo, Seyi Makinde Lu Gbẹ́dẹ Àrùn Coronavirus

Seyi Makinde, gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo pẹ̀lú àwọn tí wọ́n ti lu gbẹ́dẹ àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Gómìnà náà fi ìṣẹ̀lẹ̀ tuntun náà lédè lórí ẹ̀rọ alátagbà rẹ̀, ìyẹn Twitter ní ọjọ́ ajé. Gómìnà náà wá rọ àwọn ará ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ wípé kí wọ́n tẹ́lẹ̀ gbogbo ìlànà tí àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ elétò ìlera […]

Categories
Ìròyìn

Makinde Wọ Aṣọ Àmọ̀tẹ́kùn Láti Buwọ́lu Ìwé Àbádòfin Àmọ̀tẹ́kùn

YBTC News Yorùbá-Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ìyẹn Seyi Makinde ní ọjọ́ ìṣẹ́gun wọ aṣọ aláwọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn láti buwọ́lu ìwé òfin tí ó ma ṣe ìdásílẹ̀ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò àgbègbè ní ìpínlẹ̀ náà, léyìí tí ó ma ṣe ìdásílẹ̀ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn tí àwọn gómìnà ìwọ oòrùn gúúsù ṣe ìfilọ́lẹ̀ rẹ̀ ní àìpé yìí. Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ìpínlẹ̀ […]