Categories
Eré Ìdárayà

Ní Orílẹ̀ Èdè Spain, Wọ́n Sọ Pápá Ìṣeré Real Madrid Di Ibi Ìkó Èròjà Ìtọ́jú Àláàrẹ̀

YBTC News Yorùbá-Ikọ̀ Real Madrid ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé pápá ìṣeré Ikọ̀ ọ̀ún ni wọn ó ma lò fún ibi ìkó èròjà ìtọ́jú aláàrẹ̀ sí báyìí láti fún orílẹ̀ èdè náà ní àǹfààní láti kọjú àìsàn apanirun kòkòrò Coronavirus. Pápá ìṣeré tí ó gba kọjá ènìyàn lé lọ́nà ẹgbẹ̀rún ọgọ́rin ni wọn ó máa […]

Categories
Eré Ìdárayà

Guardiola Nírètí Wípé David Silva Yóò Lè Nínú Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ Wọn Pẹ̀lú Ikọ̀ Real Madrid

YBTC News Yoruba—Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Ikọ̀ Manchester City, Pep Guardiola ti fi ìrètí rẹ̀ hàn wípé David Silva tí ó ní ìfarapa ránpẹ́ nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí wọ́n ní gbẹ̀yìn pẹ̀lú Ikọ̀ West Ham United yóò ti padà bọ̀ sípò kí ó tó tó ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀. Silva tí ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù nípò àárín fún ikọ̀ Manchester […]

Categories
Eré Ìdárayà

Barcelona, Real Madrid Tí ń Gbìyànjú Láti Tọwọ́ Osimhen Bọ̀wé

YBTC Yorùbá-Òye tí ń fojú hàn báyìí wípé àwọn Orogún méjèèjì nínú ìdíje líígì ilẹ̀ Spain, ìyẹn Ikọ̀ Barcelona àti Ikọ̀ Real Madrid tí ń jà fitafita láti tọwọ́ agbábọ́ọ̀lú Ikọ̀ Lille, Victor Osimhen bọ̀wẹ́ bí sáà igbá bọ́ọ́lù míì ṣé ń fojú hàn. Ikọ̀ méjèèjì ni wọ́n tí ń gbìyànjú láti ṣà lékún agbára […]