Categories
Ìròyìn

Wọ́n Ti Rí Àwọn Ọmọ Ìjọ RCCG Mẹ́jọ Tí Wọ́n Gbé

YBTC News YORÙBÁ— Alámójútó gbogbo-gbò fún ìjọ RCCG, Enoch Adeboye ti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé lóòtọ́ ni àwọn ọmọ ìjọ mẹ́jọ tí wọn kó ní ọ̀ṣẹ̀ tó lọ ti rí ìtúsílẹ̀. Àwọn ọmọ ìjọ tí wọn kó ọ̀ún ni wọ́n gbé ní ọ̀nà Kachia-Kafanchan nínú ọkọ̀ ìjọ nígbà tí wọ́n ń lọ sí ilé […]

Categories
Ìròyìn

Wọ́n Ti Bèèrè Fun N50m Owó Ìtúsílẹ̀ Àwọn Ọmọ Ìjọ RCCG

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn ọmọ ìjọ RCCG mẹ́jọ tí ìròyìn gbé wípé àwon ajínigbé agbébọn gbé ni a gbọ́ wípé wọn ti bèèrè owó tó tó N50m láti fi tú wọn sílẹ̀. Olórí àgbà ijọ́ náà kan tí ó jẹ́rí sí ìlè àwọn ajínigbé yìí àti iye owó tí wọn bèèrè . Ó sàlàyé wípé […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Ọmọ Ìjọ RCCG Ni Àwọn Ajínigbé Ti Gbé Lọ Nínú Ọkọ

YBTC News YORÙBÁ— Ọkọ̀ akérò tí ó kó àwọn ọmọ ìjọ RCCG ni àwọn ajínigbé pẹ̀lú ìbọn lọ́wọ́ ti gbé lọ ní àná ọjọ́ Ẹtì, 27/03/2021, ní ìpínlẹ̀ Kaduna. Alukoro àti adarí ètò ìròyìn ìjọ RCCG, Pastor Olaitan Olubiyi, sọ èyí di mímọ̀ ní alẹ́ àná. Ṣùgbọ́n wọn ò sọ orúkọ àwọn ọmọ ijọ tí wọn […]