Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Tún Ti Gbé Òṣìṣẹ́ Kùsà Mẹ́ta Ní Ìbàdàn

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn agbébọn kan tí a fura sí gẹ́gẹ́ bí gbọ́mọgbọ́mọ ti ṣe ìkọlù sí àyè ìwakùsà kan ní ìbàdàn, ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Wọ́n kó ènìyàn mẹ́ta lọ. Orúkọ àyé ìwakùsà yìí ni Megabolex Quarry, ní ìdí Ayunre, ní ọ̀nà Ibadan-Ìjẹ̀bú Òde ní ìjọba ìbílẹ̀ Oluyole. Ní déédé aago mẹ́rin-àbọ̀ ọ̀sán ni wọ́n gbé […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Ti Ṣe Ìkọlù Sí Àyè Ìwakùsà Ní Ìbàdàn, Wọ́n Gbé Èèyàn Meji

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn agbebọn kan tí a kò mọ̀ ti ṣe ìkọlùsí àyè kan tí wọn ti ń wa kusa ní ìbàdàn, olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ní agbègbè abúlé Dali, ní pópónà márosẹ̀ Ibadan sí Ìjẹ̀bú Òde. Ìròyìn tí ó tẹ̀wá kétí jẹ́ kí á mọ̀ pé àwọn agbébọn náà yawọ àyè ìwakùsà ọ̀hún […]