Categories
Ìròyìn

Osinbajo, Àwọn Olórí Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò, Àti Àwọn Yòókù Wọlé Ìjíròrò Lórí Àwọn Ìhámọ́ra Kékèké

YBTC News Yoruba—Igbá-kejì Ààrẹ ní orílẹ̀ èdè yìí, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo àti àwọn olórí ẹ̀ṣọ́ aláàbò orílẹ̀ èdè yìí wọlé ìjíròrò ní ọjọ́ ajé ní ilé agbára, ìyẹn Aso Rock tí ó wà ní olú ìlú ilẹ̀ wa, ìyẹn ní Abuja. Lára àwọn olórí ẹ̀ṣọ́ aláàbò tí ó péjú pésẹ̀ síbi ìpàdé náà ní Ọ̀gá […]

Categories
Ìròyìn

Lórí Ọ̀rọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn, Igbá-kejì Ààrẹ àti Àwọn Gómìnà Ìwọ̀ Oòrùn Gúúsù Wọlé Ìjíròrò

YBTC Yorùbá- Ìpàdé tí ń lọ lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyìí láàrin Igbá-kejì Ààrẹ ilẹ̀ yìí, ìyẹn Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo àti àwọn Gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ní olú ìlú wa l’Abuja Ìdí ìpàdé náà kò dá lórí ọ̀rọ̀ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn tí àwọn gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀ ní ǹkan […]