Categories
Ìròyìn

Fúlàní Darandaran 50 Ni NSCDC Ti Mú Ní Òǹdó Àti Àwọn Ìpínlẹ̀ Meji

YBTC News YORÙBÁ—  Àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò tí ó ń dáàbò bo àwọn ará ìlú (NSCDC) ti mú àádọ́ta àwọn Fúlàní darandaran pẹ̀lú àwọn èlò ìjà olóró lọ́wọ́. Ọ̀gá pátápátá àjọ náà, Ọ̀mọ̀wé Ahmed Audi nígbà tí ó ń ṣe ní ṣàlàyé wípé iṣẹ́ ọwọ́ gbogbo àwọn àádọ́ta yìí ni jíjí mààlú kó àti jíji àwọn […]

Categories
Ìròyìn

Olùkọ́ Yunifásitì Kan Ní Òǹdó Ti Kú Sínú Ọkọ̀

YBTC News YORÙBÁ— Olùkọ́ kan ní ẹka ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ayé ilé ìwé ńlá Adekunle Ajasin, ìlú Àkùngbá Àkókó, ní ìpínlè Òǹdó Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọlátúndé Adégbuyi ni ó ti ìròyìn sọ pé ó kú sí inú ọkọ̀ rẹ̀. Ohun tí ó ṣe okùnfà ikú rẹ̀ kò yé wá títí di àsìkò yìí. Ọ̀kan nínú àwọn alábágbé rẹ̀ […]

Categories
Ìròyìn

Ìjọ Kérúbù Àti Séráfù Ti Ilé Ìjọsìn Mẹ́ẹ́rin Pa. Ẹ Wo Ohun Tí Wọ́n Ṣe

YBTC News YORÙBÁ— Ilé ìjọsìn Kérúbù Àti Séráfù ti sọ àgádágodo sí àwọn ẹka ilé ìjọsìn wọn mẹ́rin kan ní Àkúrẹ́ fún àwọn ìhùwàsí àìtọ́. Àwọn ilé ìjọsìn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin tí wọ́n tì pa yìí ni wọ́n sô wípé wọn kópa nínú àwọn òògùn dúdú, ẹbọ ṣíṣe, èyí tí ó lòdì sí ìlànà ìjọ tí kò […]