YBTC News YORÙBÁ— Àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti ti ìlẹ̀kùn ẹka náà pa fún ẹ̀hónú nípa ìdádúró àjọ náà. Abẹnugan ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Ọ̀yọ́, Debo Ògúndoyin ní kò bàá àwọn lójijì nítorí wọ́n ti fi tó àwọn létí. Àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti ìpínlẹ̀ Ògùn bákan náà ti ti gbogbo ilé […]
