Categories
Ìròyìn

JAMB Ti Dá Ètò Ìforúkọsílẹ Dúró

YBTC News YORÙBÁ— Àjọ tí ó ń rísí ètò ìgbaniwọlé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sí ilé ìwé ńlá ti dá ètò ìforúkọsílẹ̀ sí ilé ìwé ńlá tí ó yẹ kó bẹ̀rẹ̀ lóní dúró. Oùdarí ẹka tó ń ṣe ilana ẹgbẹ́ náà, Ọ̀mọ̀wé Fabian Benjamin ní Abùjá, ó ṣàlàyé wípé ìgbésẹ náà wáyé láti lè jẹ́ kí àwọn […]

Categories
Ìròyìn

Àfàìmọ̀ Kí Ẹni Tí kò Bá Ní NIN Má Fi Ẹ̀wọ̀n Jura

YBTC News YORÙBÁ— Mínísítà fún ètò ìbánisọ̀rọ̀ àti ọrọ̀ ajé, Ọ̀mọ̀wé Isa Pantami ojọ́’bọ̀ ti gba àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ìmọ̀ràn láti lọ̀ gbà Káàdì ìdánimọ̀ wọn. Ó ní ó ṣeé ṣe kí ẹni tí kò bá ní NIN fi ẹ̀wọ̀n jura. Ó tẹ̀síwájú wípé ìjọba àpapọ̀ kò níí gbé ẹṣẹ̀ kúrò lórí bí […]

Categories
Ìròyìn

JAMB Bẹ̀rẹ̀ Ètò Ìforúkọsílẹ. June 5 Ni Ìdánwò Bẹ̀rẹ̀

YBTC News YORÙBÁ— Àjọ JAMB ti bẹ̀rẹ̀ ètò ìforúkọsílẹ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó fẹ́ẹ́ wọ ilé ìwé gíga. Bákan náà ni wọn ti ya June 5 sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ tí ìdánwò náà yóò bẹ̀rẹ̀. Fabian Benjamin, ọ̀kan nínú àwọn olórí àjọ náà ní Bwari, FCT, nígbà tó ń sọ̀rọ̀ ní òní, ó ní […]