YBTC News YORÙBÁ— Ìlúmọ̀ọ́ká Ajìjàgbara, ajàfitafita fún ẹ̀tọ́ Yorùbá,, olóyè Sunday Adéyẹmọ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Sunday Igboho ti kéde àtìlẹ́yìn rẹ̀ fún orílẹ̀ ede ìṣọ̀kan ọmọ Yorùbá. Ó sọ èyí níbi amóhùnmáwòrán kan tó tàn ká ìkẹ̀kùn ayélujára. Ìgbòho ni gbogbo ayé tiọ̀ bí an-mọ-owó, pàápàá jùlọ bí ó ṣe gùn lé lílé […]
