Categories
Ìròyìn

Ààrẹ Ilé Aṣòfin Àgbà Ilẹ̀ Yìí Rọ Ìjọba Àpapọ̀ Láti Pèsè Ètò Irànwọ́ Fún Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Bí Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ṣe ń Jókòó Sílé Báyìí

YBTC News Yorùbá-Ààrẹ ilé Aṣòfin Àgbà ilẹ̀ yìí, ìyẹn Aṣòfin Ahmad Lawan ti ké sí ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ yìí wípé kí ó yára pèsè ètò irànwọ́ fún àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè yìí tí ó jẹ́ wípé jíjòkò sílé yóò ṣe àkóbá ńláńlá fún iṣẹ́ òòjọ́ wọn. Lawan nínú ọ̀rọ̀ tí ó fi léde láti ẹnu […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Ìjọba Ilẹ̀ Amẹ́ríkà àti Nàìjíríà Tọwọ́bọ̀wẹ́ Àdéhùn Láti Dá Owó Tí Abacha Kó Pamọ́ Sí Orílẹ̀ Èdè Amerika Padà Sí Orílẹ̀ Èdè Yìí

YBTC Yorùbá-Ìjọba Àpapọ̀ orílẹ̀ èdè yìí àti ti ìjọba ilẹ̀ Amerika ti jọ tọwọ́bọ̀wẹ́ àdéhùn báyìí wípé ìjọba ilẹ̀ Amẹ́ríkà yóò dá owó tí ó lé díẹ̀ ní Mílíọ̀nù lọ́nà Ọgọ́rùn-ún mẹ́ta owó ilẹ̀ òkèèrè padà fún ilẹ̀ Nàìjíríà, ìyẹn 308 Million Dollars. Eléyìí jẹyọ nínú ọ̀rọ̀ tí ilé aṣojú ilẹ̀ Amẹ́ríkà ní orílẹ̀ èdè […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Ilẹ̀ Nàìjíríà Ń Re Oko Gbèsè Àgbọ́lamilójú, Ọbásanjọ́ Figbe Ta

YBTC Yorùbá- Ààrẹ àná ní orílẹ̀ èdè yìí, Olóyè Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ ti figbe ta lóri bí ìṣàkóso ìjọba tí ó wà níta báyìí ṣe ń yá owó ilẹ̀ òkèèrè láti fi tukọ̀ ìjọba. Ọbásanjọ́ ní bí ìjọba Ààrẹ Muhammadu Buhari ṣe ń yá owó yóò ṣe àkóbá ńlá fún ọjọ́ ọ̀la orílẹ̀ èdè yìí, ó […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Aláàfin, Danjuma, Adébánjọ àti Àwọn Míràn Ṣe Àgbéyẹ̀wò Ọ̀rọ̀ Nàìjíríà Yẹ́bẹ́yẹ́bẹ́ Lánàá

YBTC Yorùbá – Àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà ṣe Àgbéyẹ̀wò ọ̀rọ̀ Nàìjíríà yẹ́bẹ́yẹ́bẹ́ lánàá ní ibi ìfilọ́lẹ̀ ìwé kan ti ilé iṣẹ́ ìwé ìròyìn Tribune ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀ lánàá tí ń ṣe ọjọ́ bọ̀. Lára àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ náà ni ati rí Aláàfin Ikú Bàbá Yèyé Ọba Lamidi Adeyemi. Ọ̀gá Jagunjagun tẹ́lẹ̀ rí ní ilẹ́ Nàìjíríà, Ọ̀gágun Theophilus […]