Categories
Ìròyìn

Mínísítà Fún Ètò Ìlera Kó Àrùn Kòkòrò Coronavirus Ní Orílẹ̀ Èdè Gẹ̀ẹ́sì

YBTC News Yorùbá-Mínísítà fún ètò ìlera ní orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìyẹn arábìnrin Nadine Dorries ti kó àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus. Ó sọ ọ̀rọ̀ yìí ní ọjọ́ ìṣẹ́gun, léyìí tí ó sì fàá kí àwọn ènìyàn máa rò ó wí pé àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba lè ti fara kó àrùn kòkòrò náà. Mínísítà náà sọ̀rọ̀ wípé òun […]