Categories
Ìròyìn

Ẹ Wo Arákùnrin Tó Dáná Sun Olólùfẹ́ Rẹ̀ Rí Àti Ọmọ Rẹ̀ Méjì Ní Ìbàdàn

YBTC News YORÙBÁ—  Arákùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ahmed Saka ti dáná sun olólùfẹ́ rẹ̀ rí, Mutiat Oladele àti àwọn ọmọ rẹ̀ méjì pa ilé ní ìlú Ìbàdàn. Ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú náà ṣẹlẹ̀ ní alaye Ọjọ́’rú ní Shogoye, agbègbè Ìdí-Arẹrẹ, ìlú Ìbàdàn. Ìròyìn jẹ́ kí a mọ̀ wípé Saka àti Mutiat jọ ń fara […]

Categories
Ìròyìn

Ọmọdébìnrin Kan Gún Ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ Pa Ní Òǹdó

YBTC News YORÙBÁ— Ọmọdébìnrin kan tí a mọ̀ sí Ìdòwú Bílétirí Ruth ni ìròyìn sọ pé ó ti gún ẹ̀gbọ́n rẹ̀ pa látàrí pé ó bií wípé níbo ló gbà lọ. Àjálù burúkú yìí ṣẹlẹ̀ ní agbègbè, Ìgbokòdó, olú ìlú íjoba ìbílẹ̀ Ìlàjẹ́, ní ìpínlẹ̀ Òǹdó. Ẹni tí ó wà níbi ìṣẹ̀lẹ̀ náà sọ wípé […]