Categories
Ìròyìn

Buhari Yan Oyegun Gẹ́gẹ́ Bí Alága Ìgbìmọ̀ UI

YBTC News YORÙBÁ—  Ààrẹ Buhari ti yan alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC nígbàkan rí, John Oyegun gẹ́gẹ́ bí alága ìgbìmọ̀ ilé ìwé gíga UI ní Ìbàdàn. Yàtọ̀ sí ilé ìwé UI, àwọn ilé ìwé gíga mìíràn tí ààrẹ Buhari tún yẹn àwọn ìgbìmọ̀ fún ni Yunifásítì Port Harcourt (UNIPORT), Yunifásítì Èkó (UNILAG). Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ (OAU), Ile-Ife, […]

Categories
Ìròyìn

Buhari Lọ Sí London Fún Ìlera Rẹ̀, Bí Àwọn Dókítà Ṣe Ń Múra Ìyanṣẹ́ Lódì

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn ẹgbẹ́ àpapọ̀ dókítà ibùgbé takú lórí ìpinnu wọn láti bẹ̀rẹ̀ ìyan-iṣẹ́ lódì jákèjádò orilẹ̀-èdé Nàíjíríà ní ọjọ́ ‘bọ̀. Wọ́n ní ìjọba àpapọ̀ kìí ṣe olótítọ́, wọn kìí mú àdéhùn ṣẹ. Igbákejì ọ̀gá ẹgbẹ́ náà, dókítà Arome Adejo, nígbà tí ó ń ṣojú ààrẹ ẹgbẹ́ náà, dókítà Uyilawa Okhuaihesuyi sọ pé ìjọba àpapọ̀ […]

Categories
Ìròyìn

Tinúbú Tako Buhari, Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Fún Ìlànà Ìmú-Ayé-Le

YBTC News YORÙBÁ— Adarí ẹgbẹ̀ òṣèlú APC ní Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó nígbàkan rí, Asíwájú Bọ́lá Ahmed Tinúbú ti tako ìlànà ìni-ẹni lára (austerity measures) ti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àti Buhari gbé kalẹ̀. Tinúbú sọ èyí ni Kano, níbi àpérò ẹléèkejìlá irú rẹ̀ láti fi ṣe àyẹ́sí ọjọ ìbí rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ó ṣe […]

Categories
Ìròyìn

Èmi Ò Ní Díje Dupò Mọ́ Ní Ọdún 2023, Àṣemọ Ní Mò Ń Ṣe Yìí – Ààrẹ Buhari

YBTC Yorùbá- Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ní òun kò ní díje du ipò Ààrẹ mọ́, ó sọ ọ̀rọ̀ yìí nínú ọ̀rọ̀ ìkíni kú ọdún tí ó fi ránṣẹ́ sí àwọn ọmọ Nàìjíríà ní ọjọ́ kìíní, oṣù kìíní ọdún ogún lé légbẹ̀rún ọdún, 2020. Buhari ní òun ní ìgbàgbọ́ tí ó fẹsẹ̀ rinlẹ̀ nínú ètò ìjọba […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Àwọn Krìstẹ́nì Nàìjíríà Bèèrè Ǹkan Ọdún Lọ́wọ́ Buhari, Wọ́n Ní Kó Fi Leah Sharibu Dun Àwọn Nínú

YBTC Yorùbá- Àwọn Krìstẹ́nì ilẹ̀ Nàìjíríà ti rọ Ààrẹ Muhammadu Buhari pé kó dun àwọn nínú nípa gbígba Leah Sharibu jáde kúrò lọ́wọ́ àwọn Ikọ̀ afẹ̀míṣòfò ẹgbẹ́ Boko Haram. Bíṣọ̀pù Àgbà Ìjọ Àgùdà ti Ìpínlẹ̀ Èkó, Àlùfáà Alfred Martin sọ̀rọ̀ yìí lánàá. Ó ní ó jẹ́ ǹkan tí ó ń kọni lómíinú bí àwọn jàndùkú […]