Categories
Ìròyìn

Ìjọba Àpapọ̀ Ti Sún Isopọ̀ NIN-SIM Síwájú Pẹ̀lú Oṣù Kan

YBTC News YORÙBÁ—  Ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti sún ọjọ́ tí ètò ìsopọ̀ NIN-SIM yóò wá sópin to síwájú pẹ̀lú oṣù kan gbáko. Agbẹnusọ fún àjọ NIMC jákèjádòló Nàíjíríà Káyọ̀dé Adégòkè ló sọ èyí mímọ̀ ní olú ìlú Abùjá ní àná ọjọ́ Ẹtì ní. Ìsún síwájú yìí ni wọ́n sún láti April 6, 2021 tí […]

Categories
Ìròyìn

Sòwòrẹ́ Ní Kí Àwọn Ọmọ Nàíjíríà Dá Buhari Padà Sílé Láti London

YBTC News YORÙBÁ— A-jà-fún-ẹ̀tọ́-ọmọ-ènìyàn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ọmọyẹlé Ṣòwò rẹ̀ ti ké sí àwọn ọmọ Nàíjíríà tí ó ń gbé ìlú Òyìnbó,London pé kí wọn dá ààrẹ Mùhámádù Buhari padà wá sí Nàìjíríà. Buhari ló fí orilẹ èdè Nàìjíríà sílẹ̀ lọ sí London ní àná ọjọ́ Ìṣẹ́gun fún àyẹ̀wò àlàáfíà ara rẹ̀. Tí ilé iṣẹ́ […]

Categories
Ìròyìn

Gbenga Daniel Sọ Ìdí Tí Ó Fi Dara Pọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ APC

YBTC News YORÙBÁ— Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn ní ìgbà kan rí, Ọ̀túnba Gbenga Daniel, ti sọ ìdí pàtàkì tí òun fi dara pọ̀ mọ́ egbé òṣèlú APC, ó sàlàyé pé ìdí ni pé àsàyàn pọ̀ nínú ẹgbẹ́ náà. Ó sọ èyí lẹ́yìn tí ó parí ìpàdé pẹ̀lú ààrẹ Mùhámádù Buhari ní ọjọ́ Ajé. Ó pàrọwà fún […]