Categories
Ìròyìn

Àmọ̀tẹ́kùn Àti Miyetti Allah Ṣe Ìpàdé Ní Ọ̀sun. Ẹ Wo Àbájáde Ìpàdé

YBTC News YORÙBÁ— Ẹ̀ṣọ́ àbò ilẹ̀ Yorùbá, Àmọ̀tẹ́kùn ti ẹka ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ni ìròyìn ti gbé e wípé wọ́n jọ ń ṣe ìpàdé pọ̀ pẹ̀lú àwọn Miyetti Allah fún bí ètò ọrọ̀ àbò ìpínlẹ̀ náà yóò ṣe dára. Àwọn àkójọpọ̀ ilẹ̀ Yorùbá kan tí wọn pè ní “Kiriji Heritage” to fi ẹ̀hónú ọkàn wọn lánàá […]

Categories
Ìròyìn

Ẹ Fi Sunday Ìgbòho Sílẹ̀, Ẹ Yéé Lépa Rẹ̀ – Mailafia

YBTC News YORÙBÁ— Igbákejì gómìnà ilé ìfowópamọ́ ààrin-gbùngbùn Nàìjíríà, Obadiah Mailafia ti sọ fún àwọn ẹ̀sọ́ aláàbò ọmọ ogun Nàìjíríà kí wọn ó má mú Sunday Igboho. Mailafia sọ èyí di mímọ̀ ní ọjọ́’rú. Ó sàlàyé pé Ìgbòhoń gbe ìjà àwọn èèyàn rẹ̀ ni. Ó ní ní abẹ́ òfin, àwọn ènìyàn ní ẹ̀tọ́ láti dáàbò […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Gómìnà Ilẹ̀ Yorùbá Ń Ṣe Àkóbá Fún Tinúbú Fún Ipò Ààrẹ 2023 – Miyetti Allah

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn apá kan nínú ẹgbẹ́ darandaran Miyetti Allah Kautal Hore ti sọ wípé gbogbo àwọn gómìnà ilẹ̀ Yorùbá ń ṣe àkóbá fún Asíwájú Bọ́lá Tinúbú fún èròǹgbà rẹ̀ láti du ipò ààrẹ ọdún 2023. Agbẹnusọ ẹgbẹ́ náà, Saleh Alhassan ní ọjọ́’rú tí wọn ń fi ọ̀rọ̀ wá a lẹ́nu wò nípa bí […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Yìbọn Fún Ortom

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn Agbébọn kan tí a furasí gẹ́gẹ́ bíi àgárá ọlọ́ṣà ti ṣe àkọlù sí àwọn ọkọ̀ tí Gómìnà Samuel Ortom àti àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ ń gbé lọ ní òní ọjọ́ Àbámẹ́ta. Àkolù yìí wáyé ní agbègbè  Tyo Mu ní ọ̀nà Makurdi/Gboko lọ́sán yìí. A gbọ́ wípé gómìnà ń lọ sí olú ìlú […]

Categories
Ìròyìn

Ọ̀pọ̀ Darandaran Àti Mààlúù Ni A Ò Rí Mọ́ Ní Anambra- Miyetti Allah

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn akójọpọ̀ ẹgbẹ́ darandaran Miyetti Allah ti ké gbàjarè lọ sí ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Anambra nípa àkọlù sí àwọn Fúlàní ìpínlẹ̀ náà. Àwọn ẹgbẹ́ náà sọ wípé gbogbo ìgbà ní ṣíṣe àkọlù sí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àwọn ń peléke síní àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ayamelum, ìyọ-òrùn Anambra, gúúsù Orumba àti Dunukofia. […]