Categories
Eré Ìdárayà

Manchester United Pòkọ Ìyà Fún Brighton, Newcastle Ba Ayọ̀Tottenham Jẹ́

YBTC News YORÙBÁ— Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Manchester United ní alaye yìí wá láti ẹ̀yìn fi ìyà jẹ Brighton & Hove Albion. Ayò méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni wọ́n gbá sínú àwọ̀n wọn. Bákan náà ẹ̀wẹ̀, ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Tottenham, èyí tí olùkọ́ni Jose Mourinho kó sòdí rí ìjákulẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn, Nígbà tí wọn sọ ìdíje náà di […]

Categories
Ìròyìn

Iheanacho Dáná Sun Manchester United Kúrò Ní Ìdíje FA

YBTC News YORÙBÁ— Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Leicester United lu ẹgbẹ́ Manchester United bíi ewúrẹ́ tó yalé onílé nínú ìdíje FA ní alẹ́ òní. Ayò mẹta ni wọn gbá wọlé Manchester United. Atamátáṣé agbábọ́ọ̀lù tó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Iheanacho ló gba Leicester ṣírò olú bí ó ṣe gbá ayò méjì gbankọgbì wọnú àwọn Manchester United […]

Categories
Ìròyìn

Dortmund Dọ̀tí Ara Wọn, Bayern, Madrid Àti City Fakọyọ

YBTC News YORÙBÁ— Dortmund ni ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù FC Koln dúró tí, pẹ̀lú bí wọn ṣe ta ọ̀mì ayò méjì méjì. Bayern ẹ̀wẹ̀ fi àgbà hàn akẹgbẹ́ wọn, ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Stuttgart, only lílù ọ́n no Mẹ́ẹ́rin sí òdo. Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Real Madrid náà lọ bá Celta Vigo nínú ilé wọn, wọ́n sì lù wọ́n bíi bàrà […]

Categories
Eré Ìdárayà

Gbígbá Bọ́ọ́lù Sáwọ̀n Fún Ikọ̀ Manchester United, Jẹ́ Wípé Àlá Mi Wá Sí Ìmúṣẹ

YBTC News Yorùbá-Agbábọ́ọ̀lù nípò iwájú fún ikọ̀ Manchester United, Odion Ighalo ti sọ wípé gbígbá bọ́ọ́lù sáwọ̀n fún ikọ̀ náà jẹ́ wípé àlá òun láti kékeré wá sí ìmúṣẹ. Ní oṣù kìíní ọdún yìí ni Ikọ̀ Manchester United tọwọ́ Ighalo fún àdéhùn olóṣù mẹ́fà láti Ikọ̀ tí ó wà tẹ́lẹ̀ ní orílẹ̀ èdè China. Ighalo […]

Categories
Eré Ìdárayà

Nemanja Metic Yóò Fi Ikọ̀ Manchester United Sílẹ̀ Lópin Sáà Igbábọ́ọ́lù Yìí

YBTC News Yorùbá-Gẹ́gẹ́ bí ìròyìn ṣe fìdí rẹ̀ múlẹ̀, gbajúgbajà ọmọ ilẹ̀ Serbia tí ó ń gbá bọ́ọ́lù jẹun ní ikọ̀ Manchester United ní orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì yóò fi Ikọ̀ náà sílẹ̀ lópin sáà igbábọ́ọ́lù yìí nígbà tí àdéhùn rẹ̀ pẹ̀lú Ikọ̀ náà yóò dópin. Metic kò ráyè gbá bọ́ọ́lù dáadáa lábẹ́ Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Ikọ̀ Manchester […]

Categories
Eré Ìdárayà

Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Ikọ̀ Manchester United Ṣàlàyé Ẹ̀bùn Méjì Tí Ighalo Ní

Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Ikọ̀ Manchester United ní orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìyẹn Ole Gunnar Solskjaer ti ṣàlàyé ẹ̀bùn méjì tí ó tayọ tí agbábọ́ọ̀lú tuntun fún ikọ̀ ọ̀ún ní lára. Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá náà ni a gbọ́ wípé ó ń ṣàlàyé àwọn ẹ̀bùn àmúyẹ náà nígbà tí ó ń bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ kí ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tó bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ ọjọ́rú. […]

Categories
Eré Ìdárayà

A Lè Padà Ra Odion Ighalo Sí Ikọ̀ Manchester United – Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Ikọ̀ Náà Sọ̀rọ̀

YBTC News Yorùbá-Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Ikọ̀ Manchester United, ìyẹn Ole Gunnar Solskjaer ti ṣílẹ̀kùn fún agbábọ́ọ̀lú fún ikọ̀ Super Eagles tẹ́lẹ̀ rí, ìyẹn Odion Ighalo láti sọ àdéhùn mo yà ẹ ná fún ìgbà díẹ̀ di agbábọ́ọ̀lú tuntun fún ikọ̀ náà. Ọmọ Nàìjíríà tí ó ń gbá bọ́ọ́lù jẹun ní òkè òkun náà darapọ̀ mọ́ Ikọ̀ Manchester […]