Categories
Ìròyìn

Iheanacho Dáná Sun Manchester United Kúrò Ní Ìdíje FA

YBTC News YORÙBÁ— Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Leicester United lu ẹgbẹ́ Manchester United bíi ewúrẹ́ tó yalé onílé nínú ìdíje FA ní alẹ́ òní. Ayò mẹta ni wọn gbá wọlé Manchester United. Atamátáṣé agbábọ́ọ̀lù tó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Iheanacho ló gba Leicester ṣírò olú bí ó ṣe gbá ayò méjì gbankọgbì wọnú àwọn Manchester United […]