YBTC News YORÙBÁ— Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Leeds United ti lọ bá Manchester City ní buba wọn, wọ́n lù wọ́n bíi bààrà lórí pápá ìṣeré wọn ní Etihad Ayò méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni agbábọ́ọ̀lù Leeds United Stuart Dallas gbá wọlé Manchester City, pẹ̀lú bí adarí ìdíje náà ṣe lé L.cooper kúrò ní orí pápá nígbà tí ó kù […]
