Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Àmọ̀tẹ́kùn: Àwa kò Kìí Ṣe Èèyàn Kéèyàn Ní Apá Ìwọ̀ Oòrùn Gúúsù Orílẹ̀ Èdè Yìí – Fayemi

YBTC Yorùbá- Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkìtì ti fi èsì sí ìròyìn wípé fífi lọ́lẹ̀ tí àwọn fi Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn lọ́lẹ̀ kìí ṣe fún ètò àtúntò tí àwọn kan ń pè fún tẹ́lẹ̀ rí ṣùgbọ́n láti fi kún àwọn Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò ìjọba àpapọ̀ lápá. Gómìnà náà níbi ìfilọ́lẹ̀ àwọn Ẹ̀ṣọ́ Àmọ̀tẹ́kùn lánàá ọjọ́ ọjọ́bọ sọ wípé […]