Categories
Ìròyìn

JAMB Ti Dá Ètò Ìforúkọsílẹ Dúró

YBTC News YORÙBÁ— Àjọ tí ó ń rísí ètò ìgbaniwọlé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sí ilé ìwé ńlá ti dá ètò ìforúkọsílẹ̀ sí ilé ìwé ńlá tí ó yẹ kó bẹ̀rẹ̀ lóní dúró. Oùdarí ẹka tó ń ṣe ilana ẹgbẹ́ náà, Ọ̀mọ̀wé Fabian Benjamin ní Abùjá, ó ṣàlàyé wípé ìgbésẹ náà wáyé láti lè jẹ́ kí àwọn […]

Categories
Ìròyìn

JAMB Bẹ̀rẹ̀ Ètò Ìforúkọsílẹ. June 5 Ni Ìdánwò Bẹ̀rẹ̀

YBTC News YORÙBÁ— Àjọ JAMB ti bẹ̀rẹ̀ ètò ìforúkọsílẹ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó fẹ́ẹ́ wọ ilé ìwé gíga. Bákan náà ni wọn ti ya June 5 sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ tí ìdánwò náà yóò bẹ̀rẹ̀. Fabian Benjamin, ọ̀kan nínú àwọn olórí àjọ náà ní Bwari, FCT, nígbà tó ń sọ̀rọ̀ ní òní, ó ní […]

Categories
Ìròyìn

Àjọ ICPC Ti Fi Páńpẹ́ Òfin Mú Dibu Ọ̀jẹ́rìndé Lórí Jìbìtì N900m

YBTC News YORÙBÁ— Àjọ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ jẹgúdújẹrá, ṣiṣe owó ìlú básubàsu àti àwọn ìwà burúkú mìíràn, ICPC, ló ti mú akọ̀wé ìgbàkàn rí fún àjọ JAMB, Ọ̀jọ̀gbọ́n Dibú Ọ̀jẹ́rìndé. Dibú Ọ̀jẹ́rìndé ni wọ́n ti fi páńpẹ́ òfin mú lórí ẹ̀sùn bí ó ṣe mú owó tó tó ọgọọ́un mẹ́sán mílíọ̀nu naira, N900m […]

Categories
Ìròyìn

JAMB Ti Kéde Ọjọ́ Tí Fọ́ọ̀mu Títà Yóò Bẹ̀rẹ̀ Àti Ọjọ́ Ìdánwò

YBTC News YORÙBÁ— Àjọ tó ń rísí ètò ìgbaniwọlé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti kéde fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ọ̀rọ̀ kàn wípé àwọn ti parí ètò láti bẹ̀rẹ̀ títa fọ́ọ̀mù wọn. Àwọn alákóso àjọ sàlàyé lẹ́kúnrẹ́rẹ́ wípé kí ó tóó fi ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹta ọdún yìí, àwọn yóò kéde ọjọ́ tí inú […]