Categories
Ìròyìn

Wàhálà Bẹ́ Sílẹ̀ Ní Iyana Ipaja Bí Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Ṣe Fòfin De Ọ̀kadà àti Márúwá

YBTC Yorùbá-Wàhálà, hílàhílo, àti ìjọ̀gbọ̀n bẹ́ sílẹ̀ ní Iyana Ipaja bí àwọn ènìyàn ṣe ń fẹ̀nùhùn hàn lórí bí ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ṣe fòfin de Ọ̀kadà alùpùpù àti kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́ta ní àwọn ojú pópó kan ní ìpínlẹ̀ Èkó. Nínú fọ́nrán tí wọ́n fi sí orí ẹ̀rọ alátagbà, ó hàn gba ngba wipe inúfu àyàfu […]