Categories
Ìròyìn

Àwọn Fúlàní Darandaran Ṣá Àwọn Agbẹ̀ Ṣákaṣàka Ní Ìrele-Ekiti!

YBTC News YORÙBÁ— Kò tíì tó oṣù kan tí àwọn Fúlàní darandaran pa àwọn àgbẹ̀ méjì kan jáujàku ní Isaba-Ekiti. Wọ́n tún ti ṣe àwọn àgbẹ̀ mẹ́ta mìíràn bí ọṣẹ ṣe ń ṣe ojúní Irele- Èkìtì. Nínú ìjọba ìbílẹ̀ kan náà ni àwọn ìlú méjèèjì yí wà. Àwọn Fúlàní ọ̀ún jẹ́ méfà, tí wọn sì […]