Categories
Ìròyìn

Wọ́n Ní Kí Olúwó Lọ Rọ́kúnlé Fún Oṣù Mẹ́fà Nàá – Ìgbìmọ̀ Lọ́balọ́ba Ìpínlẹ̀ Osun

YBTC News Yoruba—Olúwó ti ìlú Ìwó, Ọba Abdurasheed Akanbi ni àpapọ̀ ẹgbẹ́ àwọn lọ́balọ́ba ní ìpínlẹ̀ Osun ti ní kí ó lọ rọ́kúnlé ná fún oṣù mẹ́fà ní ọjọ́ ẹtì. Ẹgbẹ́ náà tún ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ tuntun tí Ọ̀rẹ̀gún ti ìlú Ìlá sì jẹ́ olórí ìgbìmọ̀ náà. Ìṣẹ́ ìgbìmọ̀ náà ni láti ṣe ìwádìí awuyewuye […]

Categories
Ìròyìn

Ẹ Yé Sọ Ọ̀rọ̀ Ẹ̀yìn Mọ̀ọ́, Ẹ̀gbájú Mọ́ Ètò Ìdàgbàsókè, Oyetola Sọ̀kò Ọ̀rọ̀ Sí Ẹgbẹ́ APC Ìpínlẹ̀ Osun

YBTC Yorùbá- Gómìnà Ìpínlẹ̀ Osun, Ọ̀gbẹ́ni Gboyèga Oyetola ti rọ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ All Progressive Congress (APC) ti ìpínlẹ̀ Osun pé kí wọ́n yàgò kúrò níbi ọ̀rọ̀ ẹyín, kí wọ́n gbájúmọ́ ìṣọ̀kan àti ìdàgbàsókè ẹgbẹ́ àti ìpínlẹ̀ Osun. Ó ní ìrẹ́pọ̀ àti ìṣọ̀kan láàrin ẹgbẹ́ òṣèlú náà ní ìpínlẹ̀ Osun nìkan ni ó ma ran […]