Categories
Ìròyìn

Ilé Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó Pe Àwọn Aṣòfin Tí Wọ́n Jáwe Gbéléẹ Fún Padà

YBTC News Yorùbá-Ilé Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó ti pe àwọn Aṣòfin tí ó jáwe gbélé ẹ lé lọ́wọ́ ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹta ọdún yìí padà sí ilé Aṣòfin náà. Agbẹnusọ ilé Aṣòfin náà ní ọjọ́ ọjọ́bọ kéde ìpenipadà náà ní ọjọ́ ọjọ́bọ nígbà tí Ìjíròrò ń lọ lọ́wọ́ Àwọn Aṣòfin mẹ́ta tí ọ̀rọ̀ náà kán […]

Categories
Ìròyìn

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ogun àti Èkó Ń Gbèrò Báyìí Láti Àwọn Ojúnà Kan Tí ó Wà Lọ́wọ́ Ìjọba Àpapọ̀ Fún Àtúnṣe

YBTC News Yoruba—Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ogun pẹ̀lú àjọ́ṣepọ̀ ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó tí ń gbèrò báyìí láti gba àwọn òpópónà kan tí ó so ìpínlẹ̀ méjèèjì pọ̀ kúrò lọ́wọ́ ìjọba àpapọ̀ fún àtúnṣe àti fún ìdàgbàsókè ètò ọ̀rọ̀ ajé ní ìpínlẹ̀ méjèèjì. Àwọn òpópónà tí Ìjọba ìpínlè méjèèjì ń gbèrò láti gba àtúnṣe wọn náà ni òpópónà […]

Categories
Ìròyìn

Ilé Ẹjọ́ Sọ Olùkọ́ Tẹ́lẹ̀ Rìí Ní Ilé Ìwé Gíga Ti Ìjọba Àpapọ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Èkó Sí Ẹ̀wọ̀n Ọdún Mọ́kànlélógún Lórí Ẹ̀sùn Ìfipábánilòpọ̀

YBTC News Yoruba—Ilé ẹjọ́ gíga tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó ní ọjọ́ ọjọ́bọ ti sọ olùkọ́ tẹ́lẹ̀ rí kan ní ilé ìwé gíga ti ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó, ìyẹn University of Lagos sí ẹ̀wọ̀n ọdún Mọ́kànlélógún Lórí ẹ̀sùn Ìfipábánilòpọ̀ pẹ̀lú ọmọ ọdún méjìdínlógún. Adájọ́ Josephine Oyefeso, nígbà tí ó ń […]