Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Tún Dáná Sun Ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá Mìíràn Ní Imo

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn Agbébọn ní òní ọjọ́ Ìṣẹ́gun tún ti dáná sun olú ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá mìíràn tí ó wà ní ìjọba ìbílẹ̀ Ehime Mbano ní ìpínlẹ̀ Imo. Kò tíì ju ọjọ́ kan péré lọ, nì àná tí àwọn kọ̀lọ̀rọ̀sí ẹ̀dá kan dáná sun ilé iṣẹ ọlọ́pàá tí wọn ń kó àwọn ẹlẹwọn sí, […]

Categories
Ìròyìn

Èèmọ̀! Àwọn Agbébọn Dáná Sun Ilé Ọlọ́pàá Ní Imo, Wọ́n Tú Ẹlẹ́wọ̀n Sílẹ̀

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn agbébọn kan ti dáná sun ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá tí ó wà ní Owerri, olú ìlú ìpínlẹ̀ Imo ní òru mọ́jú òwúrọ̀ yìí, ọjọ́ Ajé, April 5. Ìròyìn tí a rí sàjọ lórí ẹ̀rọ ayélujára jẹ́ kí á mọ̀ wípé ní àárín òru ni àwọn atiláawí ọ̀ún ya wọ ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Àlùfáà Ìjọ Àti Mẹ́rìnlá Mìíràn Lọwọ́ Ti Bà Fún Ìkọlù Sí llé-Iṣẹ́ Ọlọ́pàá

YBTC News YORÙBÁ—Ọwọ́ àwọn ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá tí tẹ àwọn afurasí mẹ́rìnlá kan fùn lílọ́wọ́ ṣí onírúurú ìkọlù sí àwọn òṣìṣẹ́ ọlọ́pàá àti àwọn dúkìá wọn ní àwọn ìpínlẹ̀ kan ní ìhà gúúsù-íyọ-oòrùn Nàìjíríà. Ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ní alàgbà kan ní ilé ìjọsìn mímọ́ Blessed Trinity Sabbath, Orlu, ìpínlẹ̀ Imo, Nwachukwu Egole, àti alàgbà ìjọ […]

Categories
Ìròyìn

Wọ́n Búra Fún Uzodinma, Ó Bẹ̀rẹ̀ Síní Ṣe Ìwádìí Àwọn Gómìnà Mẹ́ta Tẹ́lẹ̀ Rìí Ní Ìpínlẹ̀ Imo

Àná òde yìí ni Adájọ́ àgbà ti ìpínlẹ̀ Imo ṣe ìbúra fún Gómìnà tí ilé Ẹjọ́ sọ pé òun ni ó jáwe olúborí nínú ìdìbò gbogbogbò lọ́dún tí ó kọjá. Ìyẹn Gómìnà Hope Uzodinma jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC). Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ tí wọ́n ṣe ìbúra fún Gómìnà tuntun náà, ìyẹn Uzodinma ni ó […]