Categories
Ìròyìn

Àjọ ICPC Ti Fi Páńpẹ́ Òfin Mú Dibu Ọ̀jẹ́rìndé Lórí Jìbìtì N900m

YBTC News YORÙBÁ— Àjọ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ jẹgúdújẹrá, ṣiṣe owó ìlú básubàsu àti àwọn ìwà burúkú mìíràn, ICPC, ló ti mú akọ̀wé ìgbàkàn rí fún àjọ JAMB, Ọ̀jọ̀gbọ́n Dibú Ọ̀jẹ́rìndé. Dibú Ọ̀jẹ́rìndé ni wọ́n ti fi páńpẹ́ òfin mú lórí ẹ̀sùn bí ó ṣe mú owó tó tó ọgọọ́un mẹ́sán mílíọ̀nu naira, N900m […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Ilé Ẹjọ́ Pàṣẹ Pé Kí Wọ́n Fi Ọwọ́ Ṣù kún Òfin Mú Ọ̀gá Àgbà Aṣọ́bodè Tẹ́lẹ̀ Rí Ní Orílẹ̀ Èdè Yìí

YBTC News Yorùbá- Ilé ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ tí ó fìdí kalẹ̀ sí Abuja ti pàṣẹ pé kí wọ́n lọ fi ọwọ́ ṣù kún òfin mú Ọ̀gá Àgbà tẹ́lẹ̀ rí ní ilé iṣẹ́ aṣọ́bodè ilẹ̀ yìí, ìyẹn Nigerian Customs Service, Ọ̀gágun Abdullahi Dikko. Adájọ́ Ijeoma Ojukwu pàṣẹ wípé kí wọ́n lọ mú Dikko látàrí […]