Categories
Ìròyìn

Ẹ Wo Arákùnrin Tó Dáná Sun Olólùfẹ́ Rẹ̀ Rí Àti Ọmọ Rẹ̀ Méjì Ní Ìbàdàn

YBTC News YORÙBÁ—  Arákùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ahmed Saka ti dáná sun olólùfẹ́ rẹ̀ rí, Mutiat Oladele àti àwọn ọmọ rẹ̀ méjì pa ilé ní ìlú Ìbàdàn. Ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú náà ṣẹlẹ̀ ní alaye Ọjọ́’rú ní Shogoye, agbègbè Ìdí-Arẹrẹ, ìlú Ìbàdàn. Ìròyìn jẹ́ kí a mọ̀ wípé Saka àti Mutiat jọ ń fara […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Tún Ti Gbé Òṣìṣẹ́ Kùsà Mẹ́ta Ní Ìbàdàn

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn agbébọn kan tí a fura sí gẹ́gẹ́ bí gbọ́mọgbọ́mọ ti ṣe ìkọlù sí àyè ìwakùsà kan ní ìbàdàn, ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Wọ́n kó ènìyàn mẹ́ta lọ. Orúkọ àyé ìwakùsà yìí ni Megabolex Quarry, ní ìdí Ayunre, ní ọ̀nà Ibadan-Ìjẹ̀bú Òde ní ìjọba ìbílẹ̀ Oluyole. Ní déédé aago mẹ́rin-àbọ̀ ọ̀sán ni wọ́n gbé […]

Categories
Ìròyìn

INEC Ti Kéde Ètò Ìforúkọsílẹ Olùdìbò. Ẹ Wo Ọjọ́ Tí Yóò Bẹ̀rẹ̀

YBTC News YORÙBÁ— Àjọ tó ń rísí ètò ìdìbò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, INEC ti kédé ìgbà tí ètò ìforúkọsílẹ fún àwọn olùdìbò jákéjádò orílẹ̀-èdè yìí ní ìdá Kejì nínú ìdá mẹ́ẹ́rin ọdún. Olórí àjọ INEC lórí ẹ̀rọ ayélujára ní ìbàdàn, Wunmi Balógun sọ eléyìí di mímọ̀ ní ọjọ́ Ajé níbi ìdánilẹ́kọ́ àwọn òṣìṣẹ́ àjọ náà. Ìdánilẹ́kọ́ […]

Categories
Ìròyìn

Èèyàn Kan Ti Gbẹ́mí Mì Níbi Jàǹbá Pópónà Èkó Sí Ìbàdàn

YBTC News YORÙBÁ— Ẹnìkan ti gbẹ́mí nì níbi jàǹbà pópónà márosẹ̀ ìlú Èkó sí Ìbàdàn. Àwọn máàrún-ún ló wà níbí jàǹbà náà, tí àwọn tí ó kù sì fara pa yánnayànna. Àwọn agbófinró tó ń mójú tó ìròkèrodò ojú pópó ni ìpínlẹ̀ Ògùn, TRACE ló fìdí èyí múlẹ̀. Wọ́n ní ọkọ̀ mẹ́ta ló kópa nínú […]