Categories
Ìròyìn

Orí Yọ Ọba Èkìtì Kan Bí Àwọn Agbébọn Ṣe Yìbọn Fún-un

YBTC News YORÙBÁ—  Àwọn Agbébọn kan ní alẹ́ ọjọ́ Ẹtì ti yìbọn fún ọba alayé kan ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, ọba Elewu ti Ewu Ekiti. Ọba Adétutù Àjàyí nínú ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ rẹ̀. Ọ̀nà ayetoro-Ewu ni ọba Adétutù ń lọ ní ìjọba ìbílẹ̀ Ilejemeje. Eléyìí ṣẹlẹ̀ kò tíì ju ọjọ́ kan lọ tí àwọn agbébọn bákan náà […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Tún Ti Gbé Òṣìṣẹ́ Kùsà Mẹ́ta Ní Ìbàdàn

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn agbébọn kan tí a fura sí gẹ́gẹ́ bí gbọ́mọgbọ́mọ ti ṣe ìkọlù sí àyè ìwakùsà kan ní ìbàdàn, ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Wọ́n kó ènìyàn mẹ́ta lọ. Orúkọ àyé ìwakùsà yìí ni Megabolex Quarry, ní ìdí Ayunre, ní ọ̀nà Ibadan-Ìjẹ̀bú Òde ní ìjọba ìbílẹ̀ Oluyole. Ní déédé aago mẹ́rin-àbọ̀ ọ̀sán ni wọ́n gbé […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Ọmọ Ológun Ti Fi Bọ́m̀bù Da Àyè Ìṣápamọ Àwọn Agbébọn Imo Rú

YBTC News YORÙBÁ— Ìbẹ̀rùbojo bo gbogbo àwọn olùgbé ìjọba ìbílẹ̀ Essien Udim ní ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní alẹ́ ọjọ́ Ìṣẹ́gun pẹ̀lú bí àwọn ọmọ ológun ṣe fi bọ́ḿbù tú gbogbo inú igbó Ikot Akpan. Èròńgbà àwọn ọmọ ológun ni láti túká àti láti da àyè àkójọpọ̀ àwọn ọ̀daràn náà rú. Pàápàá pẹ̀lú bí wọ́n ṣe […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Tún Dáná Sun Ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá Mìíràn Ní Imo

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn Agbébọn ní òní ọjọ́ Ìṣẹ́gun tún ti dáná sun olú ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá mìíràn tí ó wà ní ìjọba ìbílẹ̀ Ehime Mbano ní ìpínlẹ̀ Imo. Kò tíì ju ọjọ́ kan péré lọ, nì àná tí àwọn kọ̀lọ̀rọ̀sí ẹ̀dá kan dáná sun ilé iṣẹ ọlọ́pàá tí wọn ń kó àwọn ẹlẹwọn sí, […]

Categories
Ìròyìn

Àmọ̀tẹ́kùn Ti Dóòlà Ènìyàn Mẹ́ta Lọ́wọ́ Àwọn Ajínigbé Ní Òǹdó

YBTC News YORÙBÁ—  Àwọn ikọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn ti ẹka Òǹdó ti dóòlà àwọn obìnrin méjì àti ọkùnrin kan tí àwọn àjinigbé gbé nígbà tí wọn ń bọ̀ láti ìpínlẹ̀ Benue lọ sí Àkúrẹ́ fún ìjọsìn. Orúkọ àwọn tí wọn gbé náà ni Adéwálé Adébísí, ẹni ọdún 53, méjìléláádọ́ta, Arábìnrin Ahan Mary ẹni ọdún mọ́kànlélógún àti arábìnrin […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Pa Ọmọ Ológun Nàíjíríà Maarun Ní Ìpínlẹ̀ Niger

Ènìyàn méje ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní ìpínlẹ̀ Niger ni àwọn agbébọn ti fi ìbọn já okùn ẹ̀mí wọn. Lára wọn ní ọmọ ológun máárù-ún àti àwọn ará ìlú méjì ìyókù. Àwọn ènìyàn mẹ́wàá mìíràn ni a gbọ́ pé àwọn agbébọn ọ̀hún gbé lọ. Alupùpù méje ni wọ́n jí lọ, tí wọn sì sun ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkọ àwọn ọmọ […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbénipa Ti Pa Abẹ́sinkáwọ́ Sẹnetọ Wamakko

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn agbébọn, Agbénipa ti gbé abẹ́sinkáwọ́ sẹ́nétọ̀ Aliyu Wamakko, Abba Abbey Gidan Haki, tó ti fìgbà kan rí ṣe gómìnà Sokoto, wọ́n sì ti paá pẹ̀lú. Òṣìṣẹ́ tó ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ ní akọ̀ròyìn lábẹ́ sẹ́nétọ̀ náà, Bashir Rabe Mani ti jẹrìí wípé òtítọ́ ni ìròyìn náà. Ó sọ wípé láti ojọ́ ‘bọ̀ […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Yìbọn Fún Ortom

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn Agbébọn kan tí a furasí gẹ́gẹ́ bíi àgárá ọlọ́ṣà ti ṣe àkọlù sí àwọn ọkọ̀ tí Gómìnà Samuel Ortom àti àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ ń gbé lọ ní òní ọjọ́ Àbámẹ́ta. Àkolù yìí wáyé ní agbègbè  Tyo Mu ní ọ̀nà Makurdi/Gboko lọ́sán yìí. A gbọ́ wípé gómìnà ń lọ sí olú ìlú […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Ọmọ OOU Méjì Tí Wọ́n Gbé Ti Rí Ìtúsílẹ̀

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwé gíga OOU méjì tí àwọn àjinigbé lọọ fi ipá gbe sálọ ní wọ́n ti rí Ìtúsílẹ̀. Ilé ìwé OOU èyí tí ó wà ní Ayétòrò. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà, Dàpọ̀ Abiọdun ti sọ fún aráyé lórí ìkànnì ayárabíàsá, ayélujára rẹ̀ wípé àwọn ọmọ obìnrin náà, Precious Adeyemo àti […]

Categories
Ìròyìn

Àwọn Agbébọn Ti Ṣe Ìkọlù Sí Àyè Ìwakùsà Ní Ìbàdàn, Wọ́n Gbé Èèyàn Meji

YBTC News YORÙBÁ— Àwọn agbebọn kan tí a kò mọ̀ ti ṣe ìkọlùsí àyè kan tí wọn ti ń wa kusa ní ìbàdàn, olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ní agbègbè abúlé Dali, ní pópónà márosẹ̀ Ibadan sí Ìjẹ̀bú Òde. Ìròyìn tí ó tẹ̀wá kétí jẹ́ kí á mọ̀ pé àwọn agbébọn náà yawọ àyè ìwakùsà ọ̀hún […]