Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Jonathan Farahàn Ní Aso Rock, Ó Ṣe Ìpàdé Bòńkẹ́lẹ́ Pẹ̀lú Ààrẹ Muhammadu Buhari

YBTC Yorùbá-Ààrẹ àná ní orílẹ̀ èdè yìí, Ọmọwé Goodluck Jonathan ni ó ṣà déédéé yọjú sí ilé ńlá ti ìjọba àpapọ̀ tí a mọ̀ sí Aso Rock ní olú ìlú wa Abuja ní ọjọ́ ọjọ́bọ, tí ó sì ṣe ìpàdé ráḿpẹ́ pẹ̀lú Ààrẹ Muhammadu Buhari. Ìròyìn fidi rẹ̀ múlẹ̀ wípé Ààrẹ àná náà ṣe ìpàdé […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Mi Ò Sọ Pé Mo Wà Lábẹ́ Ìwanilénilọ́rùn Láti Díje Dupò Ààrẹ Ní Ọdún 2023 – Jonathan

YBTC Yorùbá- Ààrẹ àná ní orílẹ̀ èdè yìí, Ọmọwé Goodluck Jonathan ní ọjọ́ ọjọ́rú ti sọ wípé irọ́ funfun búláú ni wípé òun sọ wípé àwọn ènìyàn tí ń wà lé òun lọrun láti díje du’pò Ààrẹ ni Ọdún 2023. Ilé iṣẹ́ ìròyìn orí ẹ̀rọ ayélujára kan ni ó ròyìn wípé Ààrẹ àná náà wà […]

Categories
Ìròyìn

Gùdùgbẹ̀ Já Lánàá Bí Àwọn Jàndùkú Agbé’bọnrìn Ṣe Kọlu Ilé Ààrẹ Àná Ní Ìlú Abínibí Rẹ̀

YBTC Yorùbá- Àwọn sùmọ̀ní Agbé’bọnrìn kọlu ilé Ààrẹ Àná ilẹ̀ wa, Olóyè Goodluck Jonathan ní ìlú abínibí rẹ̀. Buhari, Lawan, APC, PDP gbogbo wọn ni wọ́n bu ẹnu àtẹ lu ìṣẹ̀lẹ̀ náà, Wọ́n ní ẹ ṣe ìwádìí rẹ̀ dáadáa. Olobó láti ìlú Ààrẹ Àná náà tí ó ta àwọn oníròyìn lólobó sọ wípé ni déédéé […]