YBTC Yorùbá- Ìpàdé tí ń lọ lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyìí láàrin Igbá-kejì Ààrẹ ilẹ̀ yìí, ìyẹn Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo àti àwọn Gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ní olú ìlú wa l’Abuja Ìdí ìpàdé náà kò dá lórí ọ̀rọ̀ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn tí àwọn gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀ ní ǹkan […]
