Categories
Ìròyìn

Àjọ ASUP Ti Gùn Lé Ìyanṣẹ́ Lódì

YBTC News YORÙBÁ—  Àwọn òṣìṣẹ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga Polí, ASUPti gùn lé ìyanṣẹ́ lódì tí kò ní gbèdéke ọjọ́ tí wọn yóò wọlé padà nítorí àìfún àwọn òṣìṣẹ́ ní owó gidi. Ààrẹ àjọ náà, Anderson Ezeibe kéde èyí ní òwúrọ̀ òní ọjọ́ Ìṣẹgun ní Abuja. Ó ṣàlàyé pé gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ ASUP náà ló tí […]

Categories
Ìròyìn

Fi Sunday Ìgbòho Sílẹ̀, Lọ Mú Gumi Àti Àwọn Tó kù – Fálànà Sì Buhari

YBTC News YORÙBÁ— Agbẹjọ́rò àgbà fún jìjjà fún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn, Fẹmi Fálànà (SAN) ti sọ fún ìjọba àpapọ̀ tó ń lépa Sunday Kiri pé kí wọn fi í sílẹ̀. Ó ní kí ó lọ mú Sheikh Gumi ná. E rántí wípé mínísítà fún ètò ìrìnà ọkọ̀ òfurufú nígbà kan rí, Fẹ́mi Fàní Káyọ̀dé ti […]

Categories
Ìròyìn

ASUP Kìlọ̀ Fún Buhari Wípé Àwọn Ó Gùn Lé Ìyanṣẹ́ Lódì

YBTC News YORÙBÁ—Àjọ tí ó ń rí sí ilé ìwé gígaonímọ̀ ẹ̀rọ̀ polí, ASUP tí dún mọ̀hurumọ̀huru mọ́ ààrẹ Muhammadu Buhari wípé àwọn yóò gùn lé ìyanṣẹ́ lódì ní ọjọ́ kẹfaà, oṣù tó ń bọ̀. Òní ọjọ́ ẹtì ni ibi àpérò àwọn olórí wọn ní ìpínlẹ̀ Katshina. Ààrẹ àjọ náà, Anderson Ezeigbe ṣàlàyé wípé ìgbésẹ […]