Categories
Ìròyìn

Iheanacho Dáná Sun Manchester United Kúrò Ní Ìdíje FA

YBTC News YORÙBÁ— Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Leicester United lu ẹgbẹ́ Manchester United bíi ewúrẹ́ tó yalé onílé nínú ìdíje FA ní alẹ́ òní. Ayò mẹta ni wọn gbá wọlé Manchester United. Atamátáṣé agbábọ́ọ̀lù tó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Iheanacho ló gba Leicester ṣírò olú bí ó ṣe gbá ayò méjì gbankọgbì wọnú àwọn Manchester United […]

Categories
Eré Ìdárayà

Manchester City Pegedé Fún Ìpele Karùn-ún Nínú Ìdíje FA Cup

YBTC Yorùbá- Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú Manchester City ti pegedé fún ìpele karùn-ún nínú ìdíje FA Cup bí wọ́n ṣe kán Ikọ̀ Fulham lẹ́yìn ní ayọ̀ mẹ́rin sí òdo ní ilé wọn ní Etihad ní ọjọ́ àìkú. Ńìkan bí ìṣẹ́jú mẹ́fà tí ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ náà bẹ̀rẹ̀ ni Tim Ream gba káàdì pupa tí afọnfèèrè sì le jàre kúrò […]