Categories
Ìròyìn

Ìjọba Àpapọ̀ Ti Sún Isopọ̀ NIN-SIM Síwájú Pẹ̀lú Oṣù Kan

YBTC News YORÙBÁ—  Ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti sún ọjọ́ tí ètò ìsopọ̀ NIN-SIM yóò wá sópin to síwájú pẹ̀lú oṣù kan gbáko. Agbẹnusọ fún àjọ NIMC jákèjádòló Nàíjíríà Káyọ̀dé Adégòkè ló sọ èyí mímọ̀ ní olú ìlú Abùjá ní àná ọjọ́ Ẹtì ní. Ìsún síwájú yìí ni wọ́n sún láti April 6, 2021 tí […]