Categories
Ìròyìn

Dortmund Dọ̀tí Ara Wọn, Bayern, Madrid Àti City Fakọyọ

YBTC News YORÙBÁ— Dortmund ni ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù FC Koln dúró tí, pẹ̀lú bí wọn ṣe ta ọ̀mì ayò méjì méjì. Bayern ẹ̀wẹ̀ fi àgbà hàn akẹgbẹ́ wọn, ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Stuttgart, only lílù ọ́n no Mẹ́ẹ́rin sí òdo. Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Real Madrid náà lọ bá Celta Vigo nínú ilé wọn, wọ́n sì lù wọ́n bíi bàrà […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ikọ̀ Chelsea Na Everton Bi Ejò Àìjẹ Pẹ̀lú Ayò Mẹ́rin Sí Òdo

YBTC News Yorùbá-Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú Chelsea ta kọ̀ǹgbọ̀n ní ọjọ́ àìkú bí ó ṣe na Ikọ̀ Everton ní àlù bami, ó náà bi ejò àìjẹ ni pẹ̀lú ayọ̀ mẹ́rin sí òdo nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí àwọn méjèèjì jọ gbá ní ọjọ́ àìkú nínú ìdíje àgbákuta líígì ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì. Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ náà jẹ́ ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí Ikọ̀ Chelsea ti gbá […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ancelotti Ní Ikọ̀ Everton Nírètí Láti Kópa Nínú Ìdíje Europa Líígì Lẹ́yìn Tí Ikọ̀ Náà Fẹ̀yìn Crystal Palace Gbolẹ̀ Yánayàna

YBTC Yorùbá- Ipò Ikọ̀ Everton sún sókè lọsí ipò keje nínú líígì ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì bí Ikọ̀ náà ṣe fẹ̀yìn Crystal Palace gbolẹ̀ yánayàna ní ọjọ́ àbàmẹ́ta, ayò mẹ́ta sí ẹyọkan ni Everton fi fi àgbà han Ikọ̀ ọ̀ún. Bernard, Richarlison, àti Dominic Calvert-Lewin ni ó gbá àwọn bọ́ọ́lù mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọn nú àwọn fún ikọ̀ Everton. […]