Categories
Eré Ìdárayà

Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Ti Orílẹ̀ Èdè Turkey Ti Sọ Burúkú Ọ̀rọ̀ Sí Ikọ̀ Tí ó Jáwe Gbéléẹ Lé Mikel Obi Lọ́wọ́

YBTC News Yorùbá-Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí fún ìgbìmọ̀ aláṣẹ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ jáwé gbéléẹ lé Mikel Obi lọ́wọ́ tí ó tún jẹ́ Akọ́ni-Mọ̀ọ́gbá fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lú orílẹ̀ èdè Turkey ìyẹn Ozkan Sumer ti sọ ọ̀rọ̀ burúkú sí Ikọ̀ Trabzonspor lórí bí Ikọ̀ náà ṣe ní kí Mikel Obi lọ rọ́kúnlé. Bákannáà ni Sumer sọ̀rọ̀ […]

Categories
Eré Ìdárayà

Haaland Ọmọ Ọdún Mọ́kàndílógún Gbá Bọ́ọ́lù Sáwọ̀n Nígbà Ogójì Ní Sáà Igbábọ́ọ́lù Yìí

YBTC News Yoruba—Erling Braut Haaland ti gbá bọ́ọ́lù sáwọ̀n nígbà ogójì báyìí nínú gbogbo ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí ó ti kópa nínú sáà igbábọ́ọ́lù tí ó ń lọ lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyìí. Ọ̀dọ́mọdé ẹlẹ́sẹ̀ eworo lóri pápá náà tú ṣiṣẹ́ àràmàǹdà nígbà tí Ikọ̀ rẹ̀, ìyẹn Borusia Dortmund gbojú Werder Bremen yánayàna ní ọjọ́ àbàmẹ́ta nínú ìdíje àgbákuta […]

Categories
Eré Ìdárayà

Ancelotti Ní Ikọ̀ Everton Nírètí Láti Kópa Nínú Ìdíje Europa Líígì Lẹ́yìn Tí Ikọ̀ Náà Fẹ̀yìn Crystal Palace Gbolẹ̀ Yánayàna

YBTC Yorùbá- Ipò Ikọ̀ Everton sún sókè lọsí ipò keje nínú líígì ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì bí Ikọ̀ náà ṣe fẹ̀yìn Crystal Palace gbolẹ̀ yánayàna ní ọjọ́ àbàmẹ́ta, ayò mẹ́ta sí ẹyọkan ni Everton fi fi àgbà han Ikọ̀ ọ̀ún. Bernard, Richarlison, àti Dominic Calvert-Lewin ni ó gbá àwọn bọ́ọ́lù mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọn nú àwọn fún ikọ̀ Everton. […]