Categories
Eré Ìdárayà

Leeds Utd Ká Man City Mọ́lé, Wọ́n Lù Wọ́n Bíi Bààrà

YBTC News YORÙBÁ—  Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Leeds United ti lọ bá Manchester City ní buba wọn, wọ́n lù wọ́n bíi bààrà lórí pápá ìṣeré wọn ní Etihad Ayò méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni agbábọ́ọ̀lù Leeds United Stuart Dallas gbá wọlé Manchester City, pẹ̀lú bí adarí ìdíje náà ṣe lé L.cooper kúrò ní orí pápá nígbà tí ó kù […]

Categories
Eré Ìdárayà

Manchester United Pòkọ Ìyà Fún Brighton, Newcastle Ba Ayọ̀Tottenham Jẹ́

YBTC News YORÙBÁ— Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Manchester United ní alaye yìí wá láti ẹ̀yìn fi ìyà jẹ Brighton & Hove Albion. Ayò méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni wọ́n gbá sínú àwọ̀n wọn. Bákan náà ẹ̀wẹ̀, ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Tottenham, èyí tí olùkọ́ni Jose Mourinho kó sòdí rí ìjákulẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn, Nígbà tí wọn sọ ìdíje náà di […]

Categories
Eré Ìdárayà

Chelsea Gba Àlejò Ọ̀ràn, Westbrom Ba Ọmọlúàbì Wọn Jẹ́.

YBTC News YORÙBÁ—  Awọn Yorùbá máa ń pòwe wípé a ò kìí sùn nílé ẹni kí á fi ọrùn rọ́. Òwe yìí kò ṣiṣẹ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Chelsea, wọ́n gbà àlejò ọ̀ràn nì ìrọ̀lẹ́ ònì ní pápá ìṣeré wọn, Stamford Bridge. Ayò máárù-ùn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni àwọn akẹgbẹ́ wọn, West Brom Albion, tì ó wá ká […]