YBTC Yorùbá- Èkó, Ogun àti Ìpínlẹ̀ Ekiti ni ó ń léwájú nínú ètò fífi òfin de ìdásílẹ̀ Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn tí àwọn gómìnà ìwọ̀ oòrùn gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ oṣù yìí. Amòfin Àgbà ìpínlẹ̀ Ekiti tí ó tún jẹ́ Mínísítà fún ètò Ìdájọ́ ìpínlẹ̀ náà, Wale Fapohunda tí ó fi ọ̀rọ̀ […]
