YBTC News YORÙBÁ— Àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò tí ó ń dáàbò bo àwọn ará ìlú (NSCDC) ti mú àádọ́ta àwọn Fúlàní darandaran pẹ̀lú àwọn èlò ìjà olóró lọ́wọ́. Ọ̀gá pátápátá àjọ náà, Ọ̀mọ̀wé Ahmed Audi nígbà tí ó ń ṣe ní ṣàlàyé wípé iṣẹ́ ọwọ́ gbogbo àwọn àádọ́ta yìí ni jíjí mààlú kó àti jíji àwọn […]
