Categories
Ìròyìn

Orí Ìbùsùn Ni Mo Ti Bá Ìyàwó Mi Pẹ̀lú Ọkùnrin Mìíràn – Ọkọ Ìyàwó

YBTC News YORÙBÁ— Alága ìgbìmọ̀ alábẹṣékélé ẹgbẹ́ ọlọ́kadà ti ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun ti sàlàyé fún ilé ẹjọ́ abẹ́lé tí ó kalẹ̀ sí ilé tuntun ní ìlú ìbàdàn wípé àgbèrè ṣiṣe ìyàwó òun tí kọjá àfaradà. Arákùnrin ọ̀hún, Jimoh Falọlá sọ èyí di mímọ̀ nígbà tí ó ń fèsì sí ẹjọ́ ìkọni-sílẹ̀ tí ìyàwó […]

Categories
Ìròyìn

Ìyàwó Mi Ń Fi Ìbálòpọ̀ Jẹ mí Níyà. Ọkọ Ìyàwó Ké Lọ Ilé Ẹjọ́

YBTC News YORÙBÁ—  Arákùnrin kan tí ọjọ́ orí rẹ̀ kò tíì lọ jù, Joseph Manya, ní òní Ọjọ́’rú, ló ti ké gbàjarè lọ sí ilé ẹjọ́ abẹ́lé Kafanchan ní ìpínlẹ̀ Kaduna wípé kí wọn ya àwọn lọ́tọ̀ọ̀tọ̀ nítorí oorun. Manya sọ pé ìyàwó òun, Patience kìí gbà kí òun báa lájọsepọ̀. Bákan náà ni ó […]

Categories
Ìròyìn

Ìyàwó Mi Sì Ń Fi Ìbálòpọ̀ Jẹmí Níyà- Bàbá Ọgọ́rin Ọdún Ké Lọ Ilé Ẹjọ́

YBTC News YORÙBÁ— Bàbá ọgọ́rin ọdún kan tí ó ti fẹ̀yìn tì lẹ́nu iṣẹ́ olùkọ́, Ọ̀jọ̀gbọ́n Muritala Haroon, ní òní ọjọ́bọ̀ ti mú ẹjọ́ lọ sí ilé ẹjọ̀ tí ó kalẹ̀ sí Mapo wípé ìyàwó òun Afsat n fi orun jẹ òun níyà. Nígbà tí ìgbẹ́jọ́ ń lọ lọ́wọ́, Harron sàlàyé pé ìyàwó òun sì […]