Categories
Ìròyìn

Ìtànkákẹ̀ Àrùn Coronavirus Lè Fà Ọ̀wọ́n Gógó Ògùn Nílẹ̀ Nàìjíríà – NAFDAC

YBTC News Yorùbá- Àjọ tí ó ń rí sí ògùn lílò àti oúnjẹ jíjẹ ní orílẹ̀ èdè yìí, iyen National Agency for Food and Drug Administration and Control (NAFDAC) ní ọjọ́ ajé sọ wípé ìtànkálẹ̀ àrùn Coronavirus virus lè fa ọ̀wọ́n gógó ògún ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Àjọ náà sọ pé ǹkan tí ó ma […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣojú Ṣòfin Ilẹ̀ Nàìjíríà Kọ Àbá Kíkó Ọmọ Nàìjíríà Kúrò Ní Orílẹ̀ Èdè China Nítorí Àrùn Coronavirus

YBTC Yorùbá- Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ṣòfin ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọjọ́ ìṣẹ́gun ti kọ ìpè tí àwọn kan ń pè wípé kí ìjọba ilẹ̀ yìí kó àwọn ọmọ Nàìjíríà kúrò ní orílẹ̀ èdè China nítorí àrùn Coronavirus tí ó gbalẹ̀ kan ní orílẹ̀ èdè ọ̀ún. Alága fún ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin náà lórí ọ̀rọ̀ ìròyìn àti ìkéde, […]