Categories
Ìròyìn

Èyí Ni Àwọn Gbọ̀ngàn Tí Ẹ̀ Ti Lè Rí Abẹ́rẹ́ Àjẹsárá Fún Àrùn Kòrónà Gbà L’Ékó

YBTC News YORÙBÁ— Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti dárúkọ àwọn gbọ̀ngàn tí àwọn ará ìlú tí le rí abẹ́rẹ́ àjẹṣára fún àrùn kòrónà (Coronavirus) gbà. Oríṣìíríṣìí àwọn gbọ̀ngàn ogún tí ó wà káàkiri àwọn ìjọba ìbílẹ̀ jákèjádò gbogbo ìpínlẹ̀ náà tí ìjọba gbé jáde ló wà ní ìsàlẹ̀ yìí : 1 Agege KEKE Sango PHC2 Agege […]

Categories
Ìròyìn

Lórí Àrùn Kòkòrò Coronavirus, Líígì Orílẹ̀ Èdè Spain Yóò Ma Wáyé Láìsí Èrò Ìwòran

YBTC News Yorùbá-Líígì àgbà ọ̀jẹ̀ orílẹ̀ èdè Spain àti líígì tí ó tẹ̀le ni ìròyìn ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé yóò ma wáyé fún ó kéré tán ọ̀sẹ̀ méjì látàrí Ìtànkálẹ̀ Àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus tí ó yọ gbogbo ayé láàmú báyìí. Ìgbésẹ̀ náà wáyé lẹ́yìn tí àwọn ìgbìmọ̀ Aláṣẹ fún gbogbo eré ìdárayá ní […]

Categories
Eré Ìdárayà

Àwọn Agbábọ́ọ̀lù Ikọ̀ Arsenal Wà Ní Ìyàrá Àyẹ̀wọ̀ Lórí Ọ̀rọ̀ Coronavirus, Wọ́n Sún Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ Síwájú

YBTC News Yorùbá-Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí ó yẹ kí Ikọ̀ Arsenal ti orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì gbá ní ọjọ́ ọjọ́rú ní wọ́n ti sún síwájú látàrí bí gbogbo agbábọ́ọ̀lú Ikọ̀ náà ṣe wà ní ìyàrá àyẹ̀wọ̀ fún àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus. Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n ma sún ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ síwájú lórí lẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì láti ìgbà tí […]

Categories
Ìròyìn

Mínísítà Fún Ètò Ìlera Kó Àrùn Kòkòrò Coronavirus Ní Orílẹ̀ Èdè Gẹ̀ẹ́sì

YBTC News Yorùbá-Mínísítà fún ètò ìlera ní orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìyẹn arábìnrin Nadine Dorries ti kó àrùn kòkòrò apanirun Coronavirus. Ó sọ ọ̀rọ̀ yìí ní ọjọ́ ìṣẹ́gun, léyìí tí ó sì fàá kí àwọn ènìyàn máa rò ó wí pé àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba lè ti fara kó àrùn kòkòrò náà. Mínísítà náà sọ̀rọ̀ wípé òun […]

Categories
Ìròyìn

Lórí Kòkòrò Apanirun Coronavirus: Ọmọ Ilẹ̀ Ìtàló Tí ó Wà Ní Abẹ́ Àyẹ̀wọ̀ Báyìí Ń Ro Àròkàn

YBTC News Yorùbá-Komíṣọ́nà fún ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Èkó, Ọ̀jọ̀gbọ́n Akin Ayobami ti sọ ní ọjọ́ ẹtì wípé ọmọ orílẹ̀ èdè Ìtàló tíó wà ní abẹ́ àyẹ̀wọ̀ ní ilé ìwòsàn ní ìpínlẹ̀ Èkó ń ro àròkàn. Nígbà tí Komíṣọ́nà náà ń bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ lórí oun tuntun tí ó ti ṣẹlẹ̀ lórí àrùn náà, […]

Categories
Ìṣẹjúkan àti Àbọ̀

Àwọn Ọ̀nà Tí a Lè Gbà Dènà Ìtànkálẹ̀ Àrùn Coronavirus Ní Àwùjọ Wa Rèé

Àwọn Ọ̀nà Tí a Lè Gbà Dènà Ìtànkálẹ̀ Àrùn Coronavirus Ní Àwùjọ Wa Rèé Kí a ma fọ ọwọ́ wa dáadáa pẹ̀lú omi ẹnu ẹ̀rọ tí ó ń jáde tààrà. Kí a sì ma lo ọṣẹ kòkòrò tí ó ní ọtí nínú láti ma fi fọwọ́ wa. Kí o máa lo ìbọ̀wọ́ kan nígbà kan, […]

Categories
Eré Ìdárayà

Agbábọ́ọ̀lú Ọmọ Nàìjíríà Kan Ti Kó Coronavirus Ní Orílẹ̀ Èdè Ìtàló

YBTC News Yoruba—Agbábọ́ọ̀lù kan ní líígì kẹta ní orílẹ̀ èdè Ìtàló ni ìròyìn ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé ó kó àrùn Coronavirus báyìí. A gbọ́ wípé òun ni ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àkọ́kọ́ tí ó ma kó àrùn náà ní orílẹ̀ èdè aláwọ̀ funfun láti ìgbà tí àrùn náà tí ń tàn káàkiri àgbáyé. Gẹ́gẹ́ bí […]

Categories
Ìròyìn

Buhari ÓÒ, Ẹ Má Jẹ́kí Bàálù Kankan Wá Sí Orílẹ̀ Èdè Yìí Láti Orílẹ̀ Èdè Tí Coronavirus Bá ń Yọ Lẹ́nu – Atiku

YBTC News Yoruba—Igbá-kejì Ààrẹ ní orílẹ̀ èdè yìí nígbà kan rí, tí ó tún jẹ́ òǹdíje dupò Ààrẹ lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP), ìyẹn Atiku Abubakar ti gba Ààrẹ Muhammadu Buhari lámọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ Coronavirus tí ó wọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lẹ́nu lọ́wọ́ lọ́wọ́ yìí. Atiku nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ sọ pé kí […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Ẹṣọ́ra Fún Ìròyìn Ẹlẹ́jẹ̀ Lórí Ẹ̀rọ Alátagbà – Mínísítà Fún Ètò Ìlera Ṣe Ìkìlọ̀

YBTC News Yoruba—Lẹ́yìn ìkéde àrùn apànìyàn tí ó gbalẹ̀ kan ní àgbáyé, ìyẹn Coronavirus ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Mínísítà fún ètò ìlera ní orílẹ̀ èdè yìí, ìyẹn Dókítà Osagie Ehanire ṣe ìkìlọ̀ fún àwọn ọmọ Nàìjíríà níbi mímagbé Ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ kiri lóri ẹ̀rọ alátagbà, ìyẹn social media. Mínísítà náà sọ̀rọ̀ yìí nígbà tí ó ń […]

Categories
Ìròyìn

Kòsí Àyẹ̀wọ̀ Tó Péye Mí Pápákọ̀ Òfurufú Wa Fún Èèyàn Tí Ó Ní Àrùn Coronavirus Virus – Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà

YBTC News Yorùbá-Ilé Aṣòfin Àgbà Ilẹ̀ yìí ní ọjọ́ ọjọ́bọ bu ẹnu àtẹ lu ẹ̀ka tó ń rí sí ètò ìlera ní orílẹ̀ èdè yìí lóri bí ẹ̀ka náà ṣe kùnà láti dènà àrùn Coronavirus pé kí ó má wọ orílẹ̀ èdè yìí. Ilé Aṣòfin Àgbà náà wá rọ ìgbìmọ̀ ilé Aṣòfin náà lórí ètò […]