Categories
Ìròyìn

Ìjọba Àpapọ̀ Tún Ti Sèètò Àwọn Ọkọ̀ Ojú-irin Tuntun. Ẹ Wo Ìlú Tí Wọ́n Wà

YBTC News YORÙBÁ— Mínísítà tí ó ń rí sí ètò ìrìnà ní orílẹ-èdè Nàíjíríà, Rotimi Amaechi ti kéde ní àná ọjọ́ Àbámẹ́ta wípé ìjọba àpapọ̀ ti ṣetán láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ àkànṣe okọ̀ ojú-irin mẹ́ẹ́rin tuntun. Amaechi sọ èyí nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀ ní Àbújá. Lára àwọn àyè tí wọn yóò ṣe àwọn ọkọ̀ ojú […]

Categories
Ìròyìn

Èmi Ò Ní Tẹ̀lé Jonathan Tó Bá Díje Nínú Ẹgbẹ́ APC -Wike

YBTC News YORÙBÁ— Gómìnà ìpínlẹ̀ Rivers, Nyesom Wike ti sọ ìpinnu rẹ̀ wípé òun kò níí ṣe àtìlẹ́yìn fún ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí, Goodluck Ebele Jonathan. Ó sàlàyé pé kódà tí ó bá jáde díje fún ipò ààrẹ ní ọdún 2023 ní abẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú APC. Ó ní Jonatha gan fún araromi mọ̀ […]