Categories
Eré Ìdárayà

Chelsea Pòkọ Ìyà Fún Crystal Palace, Liverpool Pa Aston Villa Lẹ́kún

YBTC News YORÙBÁ— Egbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Chelsea kanra mọ́ àwọn akẹgbẹ́ wọn, Crystal Palace, wọ́n lù wọ́n bíi bẹ̀ǹbẹ́ nàbíyù pẹ̀lú àmì ayò mẹ́ẹ́rin sí ẹyọkan. Ami ayo meji kòǹgbà kòǹgbà ni Pulisic gbá wọlé kí Kurt Zouma àti Kai Havertz tóó gbá ayò kọ̀ọ̀kan wọlé. Liverpool bákan náà ẹ̀wẹ̀ fi àgbà hàn Aston Villa pẹ̀lú […]

Categories
Eré Ìdárayà

Chelsea Gba Àlejò Ọ̀ràn, Westbrom Ba Ọmọlúàbì Wọn Jẹ́.

YBTC News YORÙBÁ—  Awọn Yorùbá máa ń pòwe wípé a ò kìí sùn nílé ẹni kí á fi ọrùn rọ́. Òwe yìí kò ṣiṣẹ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Chelsea, wọ́n gbà àlejò ọ̀ràn nì ìrọ̀lẹ́ ònì ní pápá ìṣeré wọn, Stamford Bridge. Ayò máárù-ùn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni àwọn akẹgbẹ́ wọn, West Brom Albion, tì ó wá ká […]