Categories
Ìròyìn

Àwọn Ọmọ Ogun Nàíjíríà Tí Mú ISWAP 39 Balẹ̀

YBTC News YORÙBÁ— Ọkọ̀ òfurufú ọmọ ogun Nàíjíríà ti lọ kó àwọn ọmọ ogun wọn tó farapa níbi tí wọn ti ń wàákò pẹ̀lú àwọn ọmọ esin-ò-kọkú ISWAP. ISWAP jẹ́ ọkàn lára àwọn ẹ̀yaBoko Haram. Àwọn ISWAP yìí ni wọ́n ti fi ara wọn sílẹ̀ fún ISIS. Àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà ti lọ gbógun ti […]

Categories
Ìròyìn

Ìròyìn Ẹlẹ́jẹ̀ Gbáà Ni Wípé Jagunjagun Ojú Òfurufú Pa Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ọmọ Ẹgbẹ́ Afẹ̀míṣòfò Boko Haram Láìpẹ́ Yìí

YBTC Yorùbá- Àjọ jagunjagun ojú òfurufú ilẹ̀ yìí tí a mọ̀ sí Nigerian Air Force (NAF) ti sọ wípé Ìròyìn pàjáwìrì kan láìpẹ́ yìí pẹ̀lú àkọlé tí ó sọ wípé àwọn jagunjagun ojú òfurufú náà pa ọmọ ẹgbẹ́ afẹ̀míṣòfò alákatakítí ẹ̀sìn Boko Haram ọgọrun méjì lè láàdọ́ta gẹ́gẹ́bi Ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀. Agbẹnusọ fún Àjọ náà lóri […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Ààrẹ Muhammadu Buhari Ṣe Ìbẹ̀wò Sí Ìlú Maiduguri Lórí Ọgbọ̀n Èèyàn Tí Boko Haram Pa

YBTC Yorùbá- Ààrẹ Muhammadu Buhari ṣe ìbẹ̀wò sí ìlú Maiduguri ní ìpínlẹ̀ Bornu láti bá àwọn ará ìpínlẹ̀ náà kẹ́dùn lórí ìṣẹ̀lẹ̀ afẹ̀míṣòfò tí àwọn ẹgbẹ́ afẹ̀míṣòfò alákatakítí ẹ̀sìn Boko Haram ṣe ní ìlú náà láìpẹ́ yìí. Níbi ìkọlù tí àwọn ẹgbẹ́ afẹ̀míṣòfò alákatakítí ẹ̀sìn Boko Haram náà ṣe, èèyàn ọgbọ̀n ni ó fẹ̀mí ṣòfò. […]

Categories
Ìròyìn

A Tún Lè Rí Ẹgbẹ́ Afẹ̀míṣòfò Tí Yóò Tún Le Ju Boko Haram Lọ Ní Ọjọ́ Iwájú – Sultan Sọ̀rọ̀

YBTC Yorùbá- Sultan ti ìlú Sokoto, ìyẹn Alhaji Sa’ad Abubakar ti ṣe ìkìlọ̀ wípé ẹgbẹ́ afẹ̀míṣòfò tí ó tún le ju Boko Haram lọ lè ṣẹ́yọ ní ọjọ́ ọ̀la nítorí àádọ́ta àwọn ọ̀dọ́ aláìní ìyá tí wọ́n ń bẹ ní òkè ọya báyìí báyìí. Olórí náà sọ̀rọ̀ yìí ní ìpínlẹ̀ Kaduna níbi ìpàdé elétò àbò […]

Categories
Ìròyìn

A Fẹ́ Ọmọ Wa Láàyè, Yálà Ó Gbọ́mọ Tàbí Kò Gbọ́mọ Wá – Àwọn Òbí Leah Sharibu Bugbeta

YBTC Yorùbá- Àwọn òbí ọmọdébìnrin Leah Sharibu tí àwọn afẹ̀míṣòfò alákatakítí ẹ̀sìn Boko Haram fi sí àhamọ́ láti ọdún 2018 ti ṣàlàyé Ìròyìn tí ó gbalẹ̀ kan wípé ọmọ wọn bímọ gẹ́gẹ́bi Ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ lásán-làsàn. Agbẹnusọ fún mọ̀lẹ́bí náà tí ó tún jẹ́ olùkọ́ ní ilé ìwé gíga ti ìpínlẹ̀ Jos sọ fún àwọn oníròyìn […]