Categories
Ìròyìn

Buhari ÓÒ, Ẹ Má Jẹ́kí Bàálù Kankan Wá Sí Orílẹ̀ Èdè Yìí Láti Orílẹ̀ Èdè Tí Coronavirus Bá ń Yọ Lẹ́nu – Atiku

YBTC News Yoruba—Igbá-kejì Ààrẹ ní orílẹ̀ èdè yìí nígbà kan rí, tí ó tún jẹ́ òǹdíje dupò Ààrẹ lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP), ìyẹn Atiku Abubakar ti gba Ààrẹ Muhammadu Buhari lámọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ Coronavirus tí ó wọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lẹ́nu lọ́wọ́ lọ́wọ́ yìí. Atiku nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ sọ pé kí […]

Categories
Ìròyìn Tó Gbajújọ̀

Irọ́ Funfun Búláú Ni, Èmi Ò Bá Tinubu, Atiku Ṣe Ìpàdé Kankan Lórí Dídá Ẹgbẹ́ Òṣèlú Míì Sílẹ̀ – Maku

YBTC Yorùbá—Ọ̀gbẹ́ni Labaran Maku, tí ó jẹ́ Akọ̀wé Gbogbogbò ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Grand Alliance (APGA) ti ṣe àpèjúwe ìròyìn tó ní òun ṣe ìpàdé pẹ̀lú Asiwaju Bola Tinubu ti All Progressive Congress (APC) àti Atiku Abubakar ti PDP gẹ́gẹ́ bi ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀. Maku ni òun kò ní ìpàdé pẹ̀lú ẹnìkankan láti lè dá ẹgbẹ́ […]